Home / Art / Àṣà Oòduà / Odu Ifa Owonrin Elejigbo/ Otua

Odu Ifa Owonrin Elejigbo/ Otua

| |  |
| | | |
|    |
|    |

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin tu ku imura toni, mo gbaladura wipe bi a se njade lo laaro yi aori oore agbayanu lati Odo eledumare o ase.
Odu ifa OWONRIN ELEJIGBO/ OTUA lo gate laaro yi, ifa yi fore gbogbo fun akapo yi, ifa ni yio dara nkan rere orisirisi laye o ifa ni ki o bo ori re.
Ifa naa ki bayi wipe: Orunmila ni idala moni idaka, oni eleyi ti Omo eku da oni ire aje lo ba jade, Orunmila ni idala moni idaka, oni eleyi ti Omo eja da oni ire aje naa lo ba jade, Orunmila ni idala moni idaka, oni eleyi ti akapo toun naa ndayi nko oni kilo maa ba jade? Moni ire aje, aya/oko, Omo ati nkan rere gbogbo naa lo maa ba jade, moni toba wa jebi ti akapo tire ni Orunmila kini nkan to maa se ti ire naa a fi wole de ni kiakaia? Oni ti o ba se bi ti akapo toun ni, oni ki o lo ni obi meji, eja aro tutu ooye, iyo ati igba Omi tutu ki o maa fi bo ori re oni gbogbo ire ni yio je ti akapo toun.
Eyin eniyan mi, mo gbaladura laaro yi wipe gbogbo adawole wa loni yio yori si rere, eleda wa yio gba nkan rere mora, oro ayo oro idunnu ni yio maa je tiwa loni ako si ni daran ti yio ranwa lo si ogba ewon o aaaseee.
ABORU ABOYE OOO.

 

English Version

Good morning my people, how was your night? Hope it was greatly enjoyed, I pray as we are going out this morning that we shall seek the uncommon favour from God ase.
It is OWONRIN ELEJIGBO/OTUA corpus that revealed this morning, ifa foresee different kinds of goodnesses to whoever this corpus revealed out for, ifa advised him/her to feed his/her head so that he/she may be able to perform many good things in life.
Hear what the corpus said: Orunmila said idala and I said idaka, Orunmila said the one that was created by the offspring of mouse yield a lots of wealth, Orunmila said idala and I said idaka, Orunmila said the one that was created by the offspring of fish yield a lots of wealth, Orunmila also said idala and I said idaka, Orunmila said what of the one that was created by his diviner? I said it will also yield a great wealth, wife, husband, child and all good things, I now ask him(Orunmila) that what would your diviner do that will make all these goodnesses comes true? He said his diviner should offer sacrifice, two kola nuts, salt, live cat fish and a calabash of cold water to feed his/her head in order to make those goodnesses manifest quickly.
My people, I pray this morning that whatever we lay/create today will yield a great profit for us, our heads will amass a great goodness and we shall never commit an offence that will lead to jail ase.

 

Faniyi David Osagbami

About ayangalu

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

ifa

The wisdom of Ifá: True fruitfulness begins in the spirit long before it shows in the physical as the spiritual controls the physical.

In the wisdom of Ifá, we are reminded that a life aligned with divine guidance will always bear good fruit. When we walk in character, patience, and truth, the seeds we plant whether seen or unseen will surely grow in their appointed time. Do not be discouraged by slow seasons. Even the deepest roots take time to form. Stay consistent, honor your path, and trust in the wisdom of Olódùmarè. As the sacred teachings remind us: right action, right heart, ...