Orisun Kinihun ololaaju ati e ku inu igbo Itan ti a fe gbe yewo lonii ni itan Kinihun ololaaju ati eku inu igbo. Gbogbo wa la mo wi pe kinihun loba eranko. Oun naa si ni eranko to lagbara ju ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
admin Comments Off on Itan fun awon omode: Kinihun ololaaju ati eku inu igbo
Orisun Kinihun ololaaju ati e ku inu igbo Itan ti a fe gbe yewo lonii ni itan Kinihun ololaaju ati eku inu igbo. Gbogbo wa la mo wi pe kinihun loba eranko. Oun naa si ni eranko to lagbara ju ...
Read More »admin Comments Off on Mooko-mooka: Akoto ede Yoruba
Mooko-mooka: Akoto ede Yoruba Ni abala mooko-mooka ose yii, akoto ede Yoruba ni a maa gbe yewo. Akoto je ona ti n gba ko ede Yoruba sile laye ode-oni. Eleyii to yato si ti aye atijo. Aye Atijo Aye ...
Read More »admin Comments Off on Se Ruggedman ba iyawo 9ice sun looto?
Se Ruggedman ba iyawo 9ice sun looto? *Adigun Alapomeji ti pada soro *Asiri ikoko ti de gbangba Olayemi Olatilewa 9ice ati Toni Alexander Abolore Ajifolajifaola eni ti gbogbo eniyan mo si 9ice ti ni oun ko ni darijin ore oun ...
Read More »admin Comments Off on Awon omo onimoto da gobe sile ni ipinle Ondo
Orisun Awon omo egbe onimoto NURTW eka ti ijoba ibile Owo to kale si ipinle Ondo buta sira won loju lojo Isegun to koja yii. Awon iko meji kan ti won je ti egbe NURTW la gbo wi pe won ...
Read More »admin Comments Off on Nje ohun to buru wa ninu ara bibo?
Nje ohun to buru wa ninu ara bibo? Idahun awon eniyan wa ninu linki isale yii: https://www.facebook.com/photo.php?fbid=904657846286766&set=gm.1070531176331524&type=3
Read More »admin Comments Off on Taiwo Osuolale (Ibeji Oran) naa ti ku o
Lose to koja ni iroyin nipa iku Taiwo Ibeji Oran fe si wa leti, e le ka iroyin naa ninu linki isale yii. www.olayemioniroyin.com/2015/10/ki-lo-sele-si-taiwo-leyin-iku-kehinde.html Iroyin naa ti fidi mule bayii. A si tun gbo wi pe won ti sin Taiwo ...
Read More »admin Comments Off on Awon omo Iraq n fi obe ge ori ara won nibi won ti n gbadura
Awon omo orileede Iraq ti won sin orisii esin musulumi kan ti n je “Shia Islam” n fi obe ge awo ori ara won nibi won ti n gbadura.
Read More »BalogunAdesina Comments Off on Onka ede Yoruba 100 – 20,000
Orisun Onka ede Yoruba 100-Ọgọrun 110- Adọfa, àádọ́fà 120- Ọgọfa 130- Aadoje 140- Ogoje 150- Adọjọ, àádọ́jọ 160-Ọgọjọ 170-Adọsan, àádọ́sán 180- Ọgọsan 190-Mẹwadinigba 200-Igba E tesiwaju ni isale lẹhin iwe Bireki yii (Continue after the page break bellow)
Read More »BalogunAdesina Comments Off on E wo ohun ti Funke Akindele n se lowo?
Funke Akindele ti pada si ni sere idaraya eleyii to n se lati din ara sisan re ku. Awon obirin onise tiata maa n se eleyii lati mu ara awon wa ni ipo odo, eleyii to se pataki si irufe ...
Read More »BalogunAdesina Comments Off on Aye ye Rotimi Amaechi ninu Abuja
Aimoye ero wa pade Rotimi Ameachi nikete to jade ninu ile igbimo asofin Abuja lonii. Foto Rotimi Amaechi ati iyawo re leyin to yege niwaju ile igbimo asofin agba gege bi minisita ti won yan
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more