Ìlú kéréje kan wà ní ìpínlè Oyo tí orúko ìlú náà sì ń jé *ADO AWAYE*, òdó kàyééfi kan wà ní ìlú yí tí ó jé wípé bí ènìyàn bá ti esè kan bo inú rè yóò fa eni náà ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
Awoyemi Bamimore Comments Off on Odó kàyééfi ńlá tí ó wà ní *ADO AWAYE*.
Ìlú kéréje kan wà ní ìpínlè Oyo tí orúko ìlú náà sì ń jé *ADO AWAYE*, òdó kàyééfi kan wà ní ìlú yí tí ó jé wípé bí ènìyàn bá ti esè kan bo inú rè yóò fa eni náà ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Òdómokùnrin odún mókàndílógún (19 years) fé odómobìnrin odún méèdógún (15 years) ní ilè àríwá (North) ní orílè èdè Nàìjíríà.
Àwòrán tí ó gba aféfé ni ti àwon tokotayà yí tí oko jé odún mókàndílógún tí ìyàwó sì jé odún méèdógún ní ilè àríwá orílè èdè Nàìjíríà. Ò n lò èro ayélujàra kan ni ó pín àwòrán tokotayà yí, tí ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwon apàse ilé-ìwé Obafemi Awolowo University (OAU) pàse kí won mú àwon akékòó látàrí àtakò àláfíà (peaceful protest) tí won ń se.
Ogbà Obafemi Awolowo University (OAU) ti kó sí inú dàrúdàpò nígbà tí òpò akékòó tò lo sí àgó olóòpá tí ó wà ní Moore ní ìlú ile-ife láti bèèrè fún ìdásílè àwon akegbé won tí àwon ìgbìmò ìdábòbò Ogbà náà ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwòrán ìsìnkú Odudu Davis, olóòpá tí ìbon àwon olóòpá ojú omi bà tí ó sì kú ní ìpínlè calabar.
Ní’sàlé ni àwòrán ìsìnkú olóyè nínú ológun (Corporal) Odudu Davis tí ìbon pa nígbà tí osù kàrún di ogbòn ní inú odún yìí (30/5/2017)láti owó àwon olóòpá ojú omi (naval officer) nígbà tí àwon olóòpá àti àwon olóòpá ojú ...
Read More »A kú àyájó odún *Òmìnira* ti *orílè Èdè Nàìjíríà* ?? lónìí ooo. Èmí wa yóò se púpò rè láyé. E jòwó, e má sì gbàgbé láti se *ìwúre* fún orílè èdè *Nàìjíríà* ?? nítorí wí pé *”Ìròrùn igi ni ìròrùn ...
Read More »ayangalu Comments Off on Arewa Toni
ayangalu Comments Off on Oga Bello àti iyalode Binta Mogaji
Awon agba osere apanilerin meji
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ìyàwó mi dára sùgbón kò n’ìfé ìbálòpò léyìn ìgbeyàwó.
Ìyàwó mi dáa tí mo sì le pè ní aya rere sùgbón kìí gbà kí á bá ara wa lò nígbà tí ó ye, lóòtó aní omo okùnrin pèlú obìnrin. E jò ó kí ni mo le se? Mo ti ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Kílódé tí àwon omoge fi n’ìfé àwon tí ó ti n’íyàwó.
E jòwó mo fé kí e dá mi lóhùn dáadáa. Gbogbo àwon Òré mi tí ó ti n’íyàwó n’ílé ni òpò obìnrin ń súré tè lé, tí ó sì jé wípé àwon àpón bí ti àwa yí obìnrin díè ni ...
Read More »ayangalu Comments Off on Odu ifa IROSUN OSE/ALAJE
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isinmi ana o, Olorun eledumare yio jeki aje fi ile wa se ibugbe loni o ase. Odu ifa IROSUN OSE/ALAJE lo gate laaro yi, ifa yi fore aje lopolopo fun akapo ti o ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more