Home / Art (page 109)

Art

Arákùnrin kan tí won lé kúrò ní ilù òyìnbó wá sí orílé èdè Nàìjíríà nígbà tí omo rè obìnrin wà ní odún méjo (8) ti fi ara hàn nígbà tí omo rè kékòó jáde ní ilé-èkó gíga ifáfitì ti orílè èdè U.S.

    Yàtò sí wípé ó n kékòó jáde ní ilé-èkó gíga ifáfitì ti a mò sí ‘Morgan state university’, ò n lò èro ayárabíàsá (Twitter) tí a mò sí Esther Ayomide tún ní èbún pàtàkì tí ó n dúró ...

Read More »
Odu Ifa Osa Meji

Check out what Odu Ifa Osa Meji says !

Ifa advised whoever this corpus is revealed for that he/she should offer sacrifice and heed warnings, so that he/she would not go astray. Also, ifa warned him/her on any assistance that he/she may render so that he/she may not blame ...

Read More »
imo-girl

Otu nwata akwukwo nwanyi no nag bata ikpeazu ya na Mahadum di n’imo Steeti dara n’ike ma buru onye nwuru anwu!

Otu nwaagbogho no na ngalaba ikpeazu ya na Mahadum di na Imo Steeti aha ya bu Ogamba Angel Chiamaka, ka ekwuru na O dara n’ike ma nwukwazia. Nke a mere obuna mgbe ogbachitechere olu ikpeazu ya na Mahadum nke ndi ...

Read More »
ifa boy

Ifa: Obara gbedipon !

I  I II  II I I II I  II Eni odu ifa yi ba wa fun ifa kilo pe ko kiyesi awon iwa owo re gidigidi M’omode ole, maa m’agba ole, agba ole soro mu l’oko Adifa fun obara abufun ...

Read More »
ebo yoruba

Now I have done the Ebo as requested, when am I going to get my job?

A client, not a devotee said to me, “Baba Araba, now I have done the Ebo as requested, when am I going to get my job back?. I told him I can not say specifically. He said, “but baba, as ...

Read More »

Photo of the Week: Awo, Èṣù and Ọ̀rẹ̀rẹ̀

Artist: Moyo Okediji Title: Awo, Èṣù and Ọ̀rẹ̀rẹ̀ Medium: Terracotta on canvas.

Read More »

A kú osù tuntun oo.

Owó✋lá fi n sisé owó Esè la fí ñ rìnnà Olà Àtowó àtesè ki Elédùmarè má gba ìkankan nínú rè lówó wa, ká lè fi rí nñkan Ajé kó jo… Asáré pajé Arìngbèrè polà Òhun ewà ní wón jó n ...

Read More »

Arábìnrin yí ni ó wàású fún awakò yí, tí ó sì yi padà sí kìrìsìténì láti mùsúlùmí.

   Arábìnrin tí ó jé ò n lò èro ayárabíàsá (Twitter) tí a mo orúko rè sí Caramella Mou ní won fi èsùn kàn ní órí èro ayárabíàsá látàrí wípé ó wàású fún arákùnrin awakò kan tí ó jé mùsùlùmí ...

Read More »

“Èmi ni mo ni é” Adesua Etomi ni ó sobéè fún Banky W nígbà tí ó pín àwòrán ìgbéyàwó won.

   Àrídájú ti wà báyìí wípé Adesua Etomi àti Banky W ti di tokotayà, gbajúgbajà òsèré bìnrin ni ó sèsè pín àwòrán won yí tí ó sì so irú ìfé tí ó ní fun, nse ni ó dàbí eni wípé ...

Read More »

Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó ti arábìnrin tí ó tóbi àti oko aràrá.

    Nígbà tí mo rí àwòrán yí ní orí èro ayélujára , mo kókó dúró ná mo wá bi ara mi ní ìbéèrè wípé kíni obìnrin fé nínú ìgbéyàwó tàbí lára okùnrin ? Léyìn òpò ìrònú àti òpò ìrírí ...

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb