Ebó is a ritual offering or sacrifice as dictated by divination. Ebó is one of the cornerstones of Yoruba religion, and it is the tool that we have been given by the Orishas to change our fate and return our ...
Read More »Eniyan Kan Ku ni Mushin Narin Awon Omo Egbe Onijagidijagan
Rogbodiyan ti o be sile larin awon omo egbe onijagidijagan, Alamutu ati Alaka ni agbegbe kan ti a un pe ni Mushin ni ilu Eko eyi ti o fa ijamba ti o mu emi eniyan kan lo si orun aaremabo, ...
Read More »Agbajopo Ibinu da ija Eneya-meya si le, Eyi ti o mu emi Omokurin ka lo ni ilu ‘India’.
Ogogorun awon olugbe ti ẹya Indian ilu ibi ti Ọdọkùnrin ti kú, eyi ti won fura si wipe olo aloju oògùn, eyi ti o si fa rogbodiyan larin awon ati awon omo orilende ti ile Afirika eyin won un se ...
Read More »The throat of our culture and traditions
Every step we take is rhythm! Every word we speak is rhythm. We will not cut the throat of our culture and traditions. It will live on and survive.. Ase Ire O!!!! Iyalorisa Omitonade IfawemimoIfa
Read More »Jagunjagun !!!
Yoruba artist Jagunjagun 19th c.
Read More »What Ifa says in Eji Ogbe
“You call yourself a Babalawo! You send friend request to people You chat them up You asked them if they wish to consult Ifa You said you wish to help them ask about their guardian Orisa What???? Ifa said in ...
Read More »Ẹ̀rìndínlógún !
Ẹ̀rìndínlógún Èjì Ogbè Ogúnlénírinwó okọ́ Ọ̀tàlélégbèṛin àdá Wọ́n dárí jọ Wọ́n ń lọ bókè jagun Òkè kò jẹ Òkè kò mu Òkè ni yíò ṣẹ́tẹ̀ gbogbo ajogun. Twenty and four hundred hoes Sixty and eighty hundred machetes They conspired And ...
Read More »Africa is blessed with great Prophet, Orunmila(Ifa) and other Irunmole (Divinities).
We are really blessed in Africa, the Yorubaland, by Olodumare for endowing us with a great Prophet, Orunmila(Ifa) and other Irunmole (Divinities). Can you now imagine the billions of people all over the world calling the name of Orunmila simultaneously? ...
Read More »“Ìpolongo tó nlọ lọ́wọ́ ni orilẹ́ èdè Nigeria ni pe“Àyípadà bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú mi”
Ohun ti wọ́n bá fi ogún ọdún tàbi ju bẹ́ ẹ̀ lọ kọ́, ṣe é bàjẹ́ ni iṣéjú akàn, ṣùgbọ́n lati ṣe àtúnṣe lè gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún bakan na a. Ó ṣe pataki ki gbogbo ọmọ ilú pinu ni ikan ...
Read More »Obinrin kò ṣe e jánípò si ìdí Àdìrò nikan, Obinrin ló ni gbogbo Ilé
Ìtàn fi yé wa wi pé Yorùbá ka ọ̀rọ̀ obinrin si ni àṣà Yorùbá bi ó ti ẹ jẹ wi pé obinrin ki jẹ Ọba nitori ni àṣà ilú, ọkunrin ló njẹ olóri. Obinrin kò pọ̀ ni ipò agbára. Àwọn ...
Read More »