Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Olori Aina Orosun ti won je okan pataki ninu ebi Omo Yoruba Atata. Olojo ibi a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ninu ...
Read More »Se Etuntigbo ?
Pekini ? ohunareoooooooo
Read More »Kilode ti iku da emi okunrin-osere yi ni egbodo?
ojulu ni otito, ao gbo iru eleyi ri a fi d’eru ba oloro ni sugbon eleyi ko mi ni omi-inu kilo se alfa abdul-lateef titilope ifa-iwa(itakure) ki lo de ti iku da emi okunrin-osere yi ni egbodo? aaaaaaa olohun-oba aseyi ...
Read More »Arewa Toni – Oònirìsà, Àrólé Oòduà!
Ifa naa ki bayi wipe
| | | | | | | | | | | | | YORUBA VERSION: Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isimi oni, emin wa yio se pupo re laye o ase. Odu ifa OKANRAN IRORUN ...
Read More »Awada Kerikeri
Ebi de, ebi mama de ooo nibo wonti nta oka nile yi Ebami wabo wa oo
Read More »Ogulutu Oro Toni – 16.06.2016
SI GBOGBO OBINRIN Hummm obinrin sowa nu oni oko(husband) o feran oun oti gbagbe pe iwa lewa omo eniyan abi Oti gbagbe wipe bi eso oko(farm) ba da ladaju eye oko lasan ni mo pada mu ru won je. Wonyi ...
Read More »ko ko ko. Tani yen o?
Awa ni O! Eyin Wo? Awa Anu,Ire,Iyanu,Owo,OmO, Ayo,Ibukun,Alafia,Igbega,Aseyori,Aabo,Idunu,Itesiwaju, Ojurere Olorun at Emi gigun. Kini e wa o?. Awa lati wa ba iwo ati ebire/ore eyi ti o fe fun ire gbe lati odun yilo atii titi laiye… Ifa kan so ...
Read More »Arewa Asa Toni
Ayeye Ojo Ibi Iyawa Toyin Adewale Ojo ibi se koko Ojo ibi se pataki eo ni mo Ojo ibi yin saburu,Ododun ni sapo nruwe Ododun ni mariwo yo Ododun la nri omo obi lori ate, emi yin o se opo ...
Read More »Iwure Owuro 12.06.2016
E MAA WI TELE MI : *Ori mi wa gbe mi leke abinu eni. *Ori mi ko ni gbabode ibi. *Oloore mi ko ni ri mi sa *Oluwa so egan mi dogo. *Edumare wa fi ibukun sinu ise mi *Lojo ...
Read More »