The Yoruba people of South West Nigeria, are one of the largest ethnic group south of the Sahara Desert. In several ways they are one of the most interesting and important people of the continent of Africa. Their religion is ...
Read More »Owe Toni: Lati owo Jude Chukwuka
Oríkì ìbejì
Oriki Ibeji: Wíníwíní lójú orogún Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ẹ̀, Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún, Ẹdúnjobí, ọmọ a gbórí igi rétẹréte, Ọkàn ń bá bí méjì ló wọlé tọ míwá, Ọ́bẹ́kíṣì bẹ́kéṣé, Ó bé sílé alákìísa, Ó salákìísà donígba aṣọ. Gbajúmọ̀ ọmọ tíí ...
Read More »Owe Toni: Lati Owo Jude Chukwuka
Ìfé Mi (My Love)
Ìfé Mi (My Love) Eni bíi okàn mi Adúmáradán orenté Olólùfé mi àtàtà Ìfé re ní n pa mí bí otí òyìnbó Lá ì gbó ohùn re Mi ò lè sùn mi ò lè wo Léyìn re kò sí e ...
Read More »ORÍLÈ ÈDÈ MI
ORÍLÈ ÈDÈ MI Nàìjíríà ìlú mi pàtàkì Ìlú t’ókún fún ogbón Pèlú òpòlopò àwon òjògbón Ilé ogbón Tí a ti n hun àgbòn ìwà ìbàjé S’ogúndogójì di ààyò àwon òdó Òsèlú di ohun wón k’èyìn sí Egbé òsèlú di ìkan ...
Read More »Awakò kan tí kò fi ara balè ní ojú pópó ti fi okò fó orí omokùnrin kan ni ìpínlè Edo.
Òdókùnrin kan ni ó se àgbákò ikú òjijì ní ojó mélòó séyìn ní ìlú Jatu ní ìpínlè Edo, nígbà tí ó n gbìyànjú láti fònà sí òdì kejì, arákùnrin yí ni okò tí o n sáré fó ní orí tí ...
Read More »Reekado banks wà pèlú àwon òdóbìnrin tí won yááyì “ka bíbélì re kí o sì gbàdúrà lójojúmò.
Ìkan lára àwon omo olórin abé ikò Marvin, Reekado banks pín àwòrán sí orí èro ayélujára tí a mò sí instagram, èyí tí ó yà pèlú àwon òdóbìnrin tí won férè wà ní ìhòhò. Tí ó sì ko síbè pé ...
Read More »Ewe ati igi (Ọgẹgẹ́ leaf and tree)
Ewúrẹ́ ile Ẹgẹ́ kii jẹ ki wọn gun igi ọgẹgẹ Àgùntàn ile ẹgẹ kii jẹ ki wọn gun’gi ọgẹgẹ Ewe Ọ̀gẹ̀gẹ́ kii jẹ ki wọn gun Ọgẹgẹ Ọ̀gẹ̀gẹ́ igi agunla o Ọ̀gẹ̀gẹ́ ẹ oo Igi agunla o Ọbatala gun Ọ̀gẹ̀gẹ́ ...
Read More »The Devotee Of Ifá Must Be Courageous. – Holy Verse From Odu Ifá: Irete-Ose
Holy Verse From Odu Ifá: Irete-Ose “He is no coward who doesn’t run away at the noise of civil strife. Just as bees fly out of the hive but leave the hive protected. Just as ants guard their hill before, ...
Read More »