Ẹ kò nílò nọńbà ìdánimọ̀ NIN fún ìdánwò àṣewọlé ọdún 2020… Àjọ JAMB Fẹ́mi Akínṣọlá Ni báyìí Àjọ tó ń rí sí ìdánwò àṣewọlé ilé ẹ̀kọ́ gíga JAMB tí kó àfàró nípa lílo nọ́mbà ìdánimọ̀ “NIN” fún ìdánwò àṣewọlé ọdún ...
Read More »Ẹ kéde iye ọlọ́pàá tó gba rìbá, kí ẹ tó má a yin ra a yín… Aráàlú sọ fún iléeṣẹ́ ọlọ́pàá
Ẹ kéde iye ọlọ́pàá tó gba rìbá, kí ẹ tó má a yin ra a yín… Aráàlú sọ fún iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Èsì àwọn ọmọ Nàìjíríà tó tẹ̀lé bí iléèṣẹ́ ọlọ́pàá ṣe yin ara rẹ̀Lórí káàdì tí wọ́n fi síta lójú ...
Read More »Pásítò̩ ká ìyàwó pè̩lú o̩kùnrin mìíràn lórí bé̩è̩dì rè̩
Pásítò̩ ká ìyàwó pè̩lú o̩kùnrin mìíràn lórí bé̩è̩dì rè̩ Gbaju-gbaja Pastor ti gbogbo eniyan mo si Pasito Chriacus to je omo bibi ipinle Anambra amo ti o fi agbegbe Ikotun ni ilu Eko se ibujokoo ni eru Olorun tun ba ...
Read More »What is Akalamagbo Bird in English ?
Akalamagbo Bird in english
Read More »Title: Orò Ilé
Artist: Moyo OkedijiTitle: Orò IléMedium: terracottaDate: 2010
Read More »Transforming Ìṣẹ̀ṣe Temples, Shrines, Houses Of Worship
Women devotees live in a sanctuary that attends to both their spiritual and physical needs at the Àkòdì Òrìṣà. We train them to produce things that can be marketed. Spirituality is great and necessary. But we also have material needs—which ...
Read More »M C Oluo̩mo̩ fo̩wó̩ o̩lá gbáwa lójú – NURTW
MC Oluo̩mo̩ fo̩wó̩ o̩lá gbáwa lójú – NURTWLáti o̩wó̩ Yínká ÀlàbíOro ti gbogbo ara ilu ni o ti ku regbe ti o si ti di ohun igbagbe ni o tun n rugbo ni ibere ise yii laarin Musiliu Akinsanya ati ...
Read More »This is what we call Pálapàla in Ede Oodua.
Sacrilege! This man is standing up and shaking hands with the ALÁÀFIN Ọ̀YỌ̀. They say he is from Bahia. Why is he shaking hands with the Alaafin? Because he is old enough to do so? This is what we call ...
Read More »Ìjọba ti ayédèrú ilé ọmọ aláìlóbìí pa, ọmọdé mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n gbòmìnira
Ìjọba ti ayédèrú ilé ọmọ aláìlóbìí pa, ọmọdé mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n gbòmìnira Fẹ́mi Akínṣọlá Àwọn aláṣẹ tọ́rọ̀ kan lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti kó àgádágodo sílẹ̀kùn ilé ọmọ aláìóbìí kan tí kò ní wè é òfin ní ìpínlẹ̀ Kaduna, tí wọ́n sì tú ọmọdé ...
Read More »Àwọn ará ilú dáná sún èèyàn méjì tí wọ́n furasí bíi olè
Àwọn ará ilú dáná sún èèyàn méjì tí wọ́n furasí bíi olè Ọjọ́ gbogbo n t’olè, ọjọ́ kan n tolóhun.Àwọn ènìyàn méjì kan ti wọ́n fura si gẹ́gẹ́ bi olè, ni wọ́n ti dáná sun nílùú Calabar, tíí ṣe olú ...
Read More »