A young man was shot yesterday in Iwo Osun state by men of the Police (SARS) because he refused to let them check his phone. This is another strong reason the outlawed gangsters harassing the masses instead of protecting them ...
Read More »Odún ìsèsi àgbáyé
Ogúnjó osù kejo (20/8) odoodún ni odún ìsèsi màa ń wáyé káàkiri àgbáyé. Ìlú kòòkan ni ó sì máa ń se odún náà sùgbón àwon ìpínlè Kan wà tí won máa ń se é papò bí ìpínlè Osun. Àjòdún odún ...
Read More »Is there a “complete” written copy of the Odu Ifa ?
People often ask me if there is a “complete” written copy of the Odu Ifa. However, within the Odu Ifa it explains that there is no babalawo who knows all of the Odu Ifa because the pages in the Odu ...
Read More »Orin isese
Ao bo isese o, ao bo isese olowo o, isese o lao bo o, kawa to borisa o, BABA mi isese, IYA mi isese, lao bo o, kawa to borisa o, ORI mi isese, IKIN mi isese, lao bo o, ...
Read More »Water Management in Fish Farming
Experience indicates that the grade of water in fish farming isn’t just in its cleanness and clearness. Other properties of water has through the years been revealed to be of special benefit for the appropriate digestion and absorption of feed ...
Read More »Èèmò! Nígbà tí Gómìnà ìjòba ìpínlè Oyo wó ilé ìròyìn Yinka Ayefele ní ìlú Ibadan. Èyí kìí se àheso rárá, béè ní Gómìnà ìpínlè Oyo kò bá Gbajúgbajà olórin tí a mò sí Yinka Ayefele se eré rárá.
Ní òwúrò ànà tí se ojó Àìkú ní ariwo ta ní ìlú Ibadan ní ìpínlè Oyo nígbà tí ijoba ìpínlè náà pàse kí won wó ilé-isé ìròyìn ti Yinka Ayefele tí a mò sí Fresh Fm tí ó wà ní ...
Read More »Odu and Obi cast for Ose Ifa today: Ogbe Yonu
Looking at the Odu and Obi cast for Ose Ifa today, “Ogbe Yonu”, I just have to declare that we shouldn’t mind what people say about us in as much as we have the support of the great delegate of ...
Read More »A Lecture on Oshun and Gelefun: Ara Obinrin Gelefun includes; Oshun, Yemoja and Oya
Agbo ato. I am reposting a lecture I gave on Iyaami while I re set my brain to continue the conversation on the deliberate suppression of ocult wisdom A Lecture on Oshun and Gelefun by Awo Fa’lokun Fatunmbi Ara Obinrin ...
Read More »Gómìnà ìpínlè Osun kéde ojó Ajé(Monday) fún oludé fún ìsèsi tí yóò wáyé ní 20/08/2018.
Gómìnà ìpínlè Osun tí a mò sí Aregbesola ti kéde oludé fún gbogbo òsìsé ìjoba fún odún ìsèsí tí yóò wáyé ní òla ogúnjó osù kejo odún 2018.Asèyí se àmódún, ìsèsi á gbè wá oooo. Ìsèsi á gbè wá o.
Read More »Àgbàrá òjò ní ìlú Benin látàrí òjò nlá tí ó rò lánàá.
Àgbàrá òjò ní ìlú Benin látàrí òjò nlá tí ó rò lánàá. Ní òpópónà Uselu ní ìlú Benin ti ìpínlè Edo ni àgbàrá ti gbalè gbalé léyìn òjò ñlá tí ó rò . òpòlopò okò ti omi gbé lo, òpó ...
Read More »