Òrò náà só síni lénu ó tún buyò si, àbí bí èèyàn yóò bá jé òsákálá kí ó jé Òsákálá bí yóò sì jé Òsokolo kí ó ké Òsokolo, èwo ni òsákálásokolo. Èyí èèyàn sé Eléhà ni a ó pe eléyìí ni àbí Egúngún?. Eléyìí kojá òyé ti èmi.
Kí á ti è má fa òrò gún kò kúkú sí ìyàtò láàrin àwon méjèjì, èkú oko ni ìyàwó rè n wò kiri.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

