Sun re !
Read More »
Lolade Comments Off on Mayowa Ahmed dies #savemayowa
Sun re !
Read More »ayangalu Comments Off on Ìtẹ́lọ́rùn – #Ìtẹ́lọ́rùnṣepàtàkì.
Ìtẹ́lọ́rùn ni baba ìwà, Ìtẹ́lọ́rùn ṣe pàtàkì fọ́mọ adamọ, Ìtẹ́lọ́rùn ṣe kókó, A gbọdọ̀ ni ìtẹ́lọ́rùn, Kí a le rí ayé gbé, Kí a le gbáyé ìrọ̀rùn, Aìní ni ìtẹ́lọ́rùn le mú ni jalè, Bí ohun tí a ni kò ...
Read More »ayangalu Comments Off on Aṣọ wíwọ̀
Èèyàn lèyí ni àbí wèrè? Asínwín lèyí ni àbí abugije? Ṣé aṣọ lèyí abi kini? Ha! Ayé tí bàjé, Gbogbo ọmọ adáríhunrun tí sọ àṣà nù, A gbé òmíràn, A fi aṣọ sílè láìwọ̀, A sọ ìhòòhò rí rìn di ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ìfẹ́ – Èyí wa fín àwọn olólùfẹ́ láti fi ranse sí olólùfẹ́ wọn
Ẹyín féràn ẹnu,ofi ṣe ilé, Irun féràn orí ,ofi ṣe ilé, Ìràwò òwúrò tèmi nìkan, Olólùfẹ́ mi, Nínú aba ayé yìí Ẹkuro emi mi alabaku ẹwa rẹ, Ọrọ ìfẹ́ yi n yimi Mo ni mi o nífẹ̀ẹ́ mon, Ife ìwọ ...
Read More »Òmìnira ṣe pàtàkì, Òmìnira ṣe koko fún gbogbo ohun Òlódùmarè dá, Bí ènìyàn bá nínú ìnira tàbí ìgbèkùn, Tí ó wá rí ìtúsílẹ̀, Àyípadà rere a dé, Ìfọ̀kàbalẹ̀ á wà, A bọ lọ́wọ́ ìdarí ọ̀gá, A bọ nínú wàhálà ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ogboni – Isese Lagba
EEPA MOLE !!!
Read More »ayangalu Comments Off on ARUGBA is no longer a Virgin maid
Arugba is not only seen as a virgin maid any longer, she is regarded a goddess herself and people make prayers and cast all their problem on her as she bears the calabash and passes on to lead the people ...
Read More »ayangalu Comments Off on Òrúnmìla ni Baba wa o e, àwa kò ni Oba méjì, Ifá to Oba o, Òrúnmìlà ni Baba wa, Ifá to Oba o.
Oriki to Orunmila Ifá Olókun, A – sorò – dayò, Elérìn-ìpin, Ibìkejì Èdùmàrè. The Diviner of the Sea, the one who makes affairs prosper, Witness to Creation, Second to the Creator. Òrúnmìla ni Baba wa o e, àwa kò ni ...
Read More »scully009 Comments Off on Nigeria wins its 1st medal, under 23 team beats Honduras 3-2
Nigeria wins its first medal as under 23 team beats Honduras 3-2 to win the Bronze medal. This is the only medal for Nigeria in the 2016 Rio Olympics. Congrats!!!
Read More »Lolade Comments Off on ‘So far Buhari has not disappointed us, I trust him’ – OBJ
Former President Olusegun Obasanjo has expressed confidence that President Buhari will surmount the current challenges confronting the country. Based on him, President Buhari has up to now not disappointed Nigerians. The former President said this in Jalingo yesterday August 19th. ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more