Olùsò àgùntàn tí a mò sí pásítò Adeboye tí ó jé olórí àwon omo léyìn Jésù ti ìjo RCCG fún àwon akékòó ìmò adajó tí ó yege jùlo mérin ní Fìlà orí ri awon adájó àti aso won.
Olórí àwon olùfokànsìn àti omo léyì jésù ti Ìjo àwon RCCG, gbogbo àgbáyé, Pásítò E.A Adeboye fún àwon akékòó tí won sèsè gboyè gégé bíi adájó mérin nínú ìjo rè ní àgbàlá HALL OF MERCY, Bwari ní ìpínlè Abuja, ní ...
Read More »