Home / Art / Àṣà Oòduà / Alibaba tako Anthony Joshua nígbà tí ó ya àwòrán Láì wo aso tí àwon èyà ara rè sì hàn.

Alibaba tako Anthony Joshua nígbà tí ó ya àwòrán Láì wo aso tí àwon èyà ara rè sì hàn.

Anthony Joshua ní láti gbáradì fún ogun míràn báyìí ni Alibaba tí Ó jé apanilérìn-ín àti adérìn-ín pa òsónú se so nígbà tí Anthony fi aya rè hàn tí èyí sì fi hàn wípé okùnrin mésàn-án ni, òun náà sì ya àwòrán ara rè hàn wípé kí Anthony Joshua gbáradì nítorí òun yóò se tán títí odún méjì.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti