Home / Art / Àṣà Oòduà / Arábìnrin tí kò ju omo odún métàdínlógún (23) lo ta omo rè òsé méfà tí ó sí fi owó rè ra èro ìbánisòrò ní ìpínlè Edo.

Arábìnrin tí kò ju omo odún métàdínlógún (23) lo ta omo rè òsé méfà tí ó sí fi owó rè ra èro ìbánisòrò ní ìpínlè Edo.

Owó àwon agbófinrín ti te arábìnrin kan ní ìpínlè Edo tí ó jé ìyá omo méjì , Miracle Johnson, fún títa omo rè omo òsè méfà tí ó sì di owó náà ra èro ìbánisòrò fún ara rè.
Gégé bí ìwé ìròyìn Punch se so, Miracle jé omo bíbí ilú Agenenbode ní Etsako ìjóba ìbílè ìwó oòrùn ti ìpínlè náà, ta omo rè sí ilé àwon omo òrukàn fún élegbérún lónà igba náírà (#200,000) .
Miracle so wípé won ti òhun ni láti ta omo náà nítorí àìlówó lówó, àìrí nkan je .

Send Money To Nigeria Free

About Awoyemi Bamimore

x

Check Also

Deborah Samuel

Why are Nigerian celebrities keeping quiet over Deborah Samuel’s gruesome murder

I remember when George Floyd was killed in America by white police officers, Nigerians protested in Abuja and Lagos. I’m not saying that was bad though, he was a black man like me. But here is my grouse, Africans, and Nigerians, in particular, are always quick to show support when something happens elsewhere, but they will not do anything when it comes to fellow Nigerians. By now, there should be massive protests across the country demanding justice, but none of ...