Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwon Jagunjagun tí a mò sí Soldier ti pa ìko àwon Boko Haram ní Arege, Borno, tí won sì gbà àwon ohun ìja olóró ní owó won.

Àwon Jagunjagun tí a mò sí Soldier ti pa ìko àwon Boko Haram ní Arege, Borno, tí won sì gbà àwon ohun ìja olóró ní owó won.

Two Ikò Boko Haram ti fi ojú winá ogun won sì ti bá ogún lo, tí ojú won sì rí méwàá ni ojó kejìlélógbòn osù kokànlá odún 2018 nígbà tí won tún fé se bí ìse won ní Arege ní ìjoba ìbílè Mobbar ní ìpínlè Borno.
Àwon akoni wa ti kojú ogún dàwón won sì ti jéyán won nísu.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

iwure tooni

#Iwure Owuro Tooni lati enu Kolawole Ifarotimi

Iba Olodumare. Iba Akoda Aye, Iba Aseda Aye, Iba Eniyan. Ekaro, eku ojumon. Ojumon ire gbogbo. Loni, Olodumare yoo silekun gbogbo ire fun o yoo si ti ilekun ibanuje, ekun, ipayin keke pa. Lori jije ati mimun re loni, ooni gbe omi p’ari, oosi niigbe ata pari gbona orun lo pelu. Ina ola re konii joku rebete. Ooni fo loju, ooni ro lapa ro lese. Gbogbo ire ti o ti wo agbole re, koni pada baje. Ooni fi eda re ...