Home / Art / Àṣà Oòduà / E ku ojumo eyin omo ile kaaro ojiire. Se daada ni?

E ku ojumo eyin omo ile kaaro ojiire. Se daada ni?

Mo gba l’adura wipe bi a tin jade lo fun ise oojo wa, ao ni ko el’esu l’ona. Iko ki n ko ejo l’ese, ayun lo ayun bo l’owo n yun enu. Atepe ni ese n te’na. Ire ila oorun, iwo oorun, gusu oun ariwa ki eledua gbe ko wa. A pa m’owo owo, ata jere oja.

yoruba

Ewe gbegbe ko gbe ire to wa wa,
ewe ewuro ko je ki oloore wa ko mu ti wa ro.
Ona ki n di mol’oko, ona ki n di mo al’ada, ona ko ma se di mo wa.
Ire l’oju owo nri, ire la o ma ri.

Aseye ni alakan n s’epo, aseye la o se.

Ase

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Ọbàtálá

A kú ọ̀sẹ́ Òrìṣà [Ọbàtálá]

Éèpà ÒrìṣàMo ṣẹbà aṣẹ̀dá!Mo ṣèbà Ọba àlà funfunỌba ńlá o jíreWa túnbọ̀ tàlà bòmí,Àlábàláṣẹ! Happy Ọbatala worship day Obatala #Oriṣanla #Ancestor #Yoruba#Decolonization