Ní òní mo gbèrò láti tún ilé àti àyíká Adìe mi se, ni mo pàdé afayàfà yí, mo sá eré bí mo se le sa mo. Nítorí ìgbà àkókò mi rè é tí mà rí ejò ńlá báyìí láàyè, tí kìí bá se lopélopé omokùnrin kan tí mo pàdé, mo rò wípé ejò náà kò bá bó mó mi lówó.
Èyin tí e n’ìfé Ejò n’ílé irú èyà wo ni eléyìí báyìí..
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more


Wow!! O tobi gan abi?
Beeni o..