(Ìwà)
Amúyan abìtanná yanranyanran
Adia’fun orunmila babá o tanná fórìsà riwa
Ebo lawo ni kose
Ógbébo órúbo
Ógbèrù ótèrù
Njé ifá tan sílé, èdú tan sónà
Tan ni o mòpé ina ire lope ntan
Bàbá arúgbó that:
Sleeps in purity
Rise in purity
The great craftman that mould
eminence into human beings
The most purity that dwell in white
#Oturupon_rosun
Òrìsà májekí ìwà mi o bàjé…Àsē o
-Awo
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

