Home / Art / Àṣà Oòduà / Odún ifá àgbáyé !
ifa

Odún ifá àgbáyé !

Odù ifá tí ó sòkalè ni *ìretè-ìká* ifá pé ire aya (couples blessing) ifá ní a ó se òpòlopò Odún láyé.

Ifá ní kí á rúbo lópòlopò wípé Odún yìí yóò sàn wá fún ajé, aya, Omo, ogbó ató àti àìkú tí se baálè orò .

Àsèyí se àmòdún ooo

About Awoyemi Bamimore

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

ifa on sex

Ifa on Sex and Sex Positions With Owomide Ifagbenusola