Home / Art / Àṣà Oòduà / Ohun méje tí ó jé èdùn okàn tí won kò so fún mi kí n tó parí ilé-èkó gíga ifáfitì.
parí ilé-èkó gíga ifáfitì.

Ohun méje tí ó jé èdùn okàn tí won kò so fún mi kí n tó parí ilé-èkó gíga ifáfitì.

Ohun méje (7) tí ó jé èdùn okàn tí enikéni kò so fún mi kí n tó parí ilé-èkó gíga.

1- ilé-èkó gíga ifáfitì wà fún mímo irú èèyàn tí o jé, lo àkókò àti ànfààní tí o bá ní dáadáa, láti mo ìlépa re tí ó jé wípé nígbà tí o bá se tán o kò ní fi àkókò re s’òfò.

2- ní ìlépa tó dáńgájíá.

3- tí o bá ní èbùn tàbí ohun tí o féràn láti ma se má fi àkókò s’òfò láti sin enikéni! Lépa ònà tìre.

4 – má jè é kí enikéni so fún o wípé “o kò le se é”.

5- Gbìn sínú okàn re má sì jé kí okàn re rè sí isé òòjó re : èkó lórí ara eni (self study), èkó àgbà (post grad study), isé re (courses), eré ìdárayá (sport), kíka ìwé (reading) Àpérò (seminar) ìrìnàjò (travelling), èdè (linguistic).

6- má gbé okàn lé ònà àtije kan, gbìyànjú láti ní ònà míràn.

7- tí o bá pinnu láti sisé l’ábé enikéni ó ye kí o mò wípé ìgbéga re ó dá lórí òsùwòn 40% fún isé kára kára àti 60% òsèlú tí ó sì jé wípé kò ní sú e….

Continue after the page break for English Version

Send Money To Nigeria Free

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

The Èkó(s) of the Oòduà (Yorùbá) Homeland.

Èkó-Ènde (Ìfẹ́lódùn LGA, State of Ọ̀ṣun)Èkó-Àkéte (Lagos Island LGA, Lagos State)Èkó-Àjàlá (Ìfẹ́lódùn LGA, State of Ọ̀ṣun)Èkó – Efun ( Amongst The Olukumi of Delta state) 2021 Edition of the Ọ̀tín-Èkó Festival where the Ọ̀tín River is celebrated by the Èkó people around the River in Ọ̀ṣun. Ọtín River is a very important one in Yorùbá history. It was the river that drowned the highest number of terrible invaders of the Homeland in the Jálumi war of November 1, 1878.In fact, ...