Home / Art / Àṣà Oòduà / Òkan l’ára àwon anamoyayà (civil defence officer) ni àwon fúlàní darandaran pa ní ìpínlè Benue tí won sì sin ín pélú omijé.

Òkan l’ára àwon anamoyayà (civil defence officer) ni àwon fúlàní darandaran pa ní ìpínlè Benue tí won sì sin ín pélú omijé.

Anamoyayà (civil defence officer) ni àwon Fulani darandaran pa ní ìjoba ìbílè Guma ní ìpìnlè Benue ni won ti sín pèlú òpòlopò omijé. Àwon emèwà rè ti sin ín tomijé tomijé.

Send Money To Nigeria Free

About Awoyemi Bamimore

x

Check Also

Ọdún orò gbìnà yá, ìdájí ní àwọn olórò yóò fi máa yíde ìlú níṣẹ̀yin

Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣe aifẹsọ kebosi,lai rẹni jo o,ati pe n ta o ba fẹ o bajẹ,o ni bi o ṣe yẹ ka ṣe e,eyi lo bi atunse abẹnu lati fopin sawuye wuye to waye latari aawọ to suyọ laarin awọn onisese ati awọn ẹlẹsin meji ti o ku(Kitẹẹni ati Musulumi).Wayi o, igbakeji alaga fun ẹgbẹ agbaagba nilu Isẹyin, Alhaji Bọlaji Kareem, ti kede pe ija ti dopin, ogun si ti tan lori aawọ ọrọ sise nilu Isẹyin.Kareem, ẹni to soju ...