Obìnrin àkókó ní inú egbé Marvin kúnlè wò ní orí ìkúnlè nígbà tí ó kí ògà gun àti ògbóntàgirigì tí a mò sí Shina Peter nígbà tí won n sí ilé-isé pefume brand, Sappire Scent ní Lenox mall ní ìpínlè Eko.
Bákan náà, won tún sí ojú olú polówó ojà won tí a mò sí Cee-C.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more


