Edward Campbell, eni odun mokandinlaadota (49) ni won ti gbe lo si ile ejo lojo Eti to koja yii pelu esun wi pe o gun pasito Redeemed Christian Church of God (RCCG), Dotun Olojede, lo be. Ile ejo Majisireeti to ...
Read More »Otun Olubadan tile Ibadan ti dagbere faye
Otun Olubadan ti ile Ibadan, to tun je okan pataki ninu awon agba oye ile Ibadan, Omowale Kuye, ti dagbere faye leni odun metadinlaadorun (87). Oloye yii la gbo wi pe o dake ninu ile re to wa ni agbegbe Ikolaba ...
Read More »Abule wo ni sisi yii ti wa na?
Eleyii tun gaju!
Read More »Question of The Day: What Is Ifa ? ( See Answer )
What Is Ifa : Ifa is a connector between Eledumare (God) and mankind. Ifa is not a Confusionist and neither he’s a traitor. Ifa explains the rationale behind wealth, sorrow, success, failure, sickness, death and the likes, and ensurs purity ...
Read More »E wo ohun ti won fi ibeji da lara
Nje e le biliifu eleyii? Awon ibeji okunrin meji fe awon ibeji obirin kan naa. Awon pasito meji to so won po, ibeji ni won. Awon ore iyawo meji to tele won, ibeji ni won. Awon omo iyawo obirin, ibeji ...
Read More »Ofiisi Fasola tuntun: Ise minisita ti bere ni perewu
Minisita fun ise ode, mona-mona ati eto ilegbe ti bere ise lofiisi re tuntun lana ojo Aje, Monde.
Read More »Arun oju: Ohun ti e o se ti oju ba n su tabi yun yin
Ti oju ba yun eniyan, tabi ti oju naa ba n su. Olayemi Oniroyin ti lo sewadii nipa ona ti eniyan fi le setoju iru oju bee lona to rorun ju lo. Ti eni naa yoo si bo ninu wahala ...
Read More »Mercy Aigbe alaso oge pade Toke Makinwa
Awon Yoruba bo, won ni tode-tode ni i se alaso tuntun. Joojumo ni Mercy n sodun, Mercy Aigbe alaso oge. Mercy tun pade Toke, sorosoro ori redio ati telifisan ti oun naa feran oge lagbo ariya.
Read More »Dayo Amusa ti pada senu ise
Dayo Amusa wa lara awon ero Mecca odun yii pelu awon akegbe re bi Fathia Balogun ni won jo goke arafa papo. Igba ti won de ni won di Alaaja tuntun. Sugbon bayii, Dayo ti pade sidi ise oojo re nibi ...
Read More »Eleleture lati owo Akeem Lasisi
Eyi ni fidio orin ewi lati owo Akeem Lasisi ti won pe akole re ni ELELETURE
Read More »