Ohun ti Ogbeni Yanju Adegboyega ko nipa maanu naa ni yii: “Walaaahi! Mo sese gbagbo loooto ni pe, alaimoore lo po julo ninu awon oloselu. Olorun n gbo, alaimoore ni Aare Buhari ati egbe oselu APC. Eyin o gbagbo? O ...
Read More »Okiki fi Oore Ofe gbe Femi Solar jade: Fidio orin tuntun yii leku!
Femi omo Oladele ti gbobo eniyan mo si Femi Solar ti fi gbogbo awon ololufe re lokan bale pelu fidio orin re tuntun to pe ni GRACE nigba to n fi die ninu fidio naa to won lenu won. Gege ...
Read More »O se o Eledua ! Alaafia ti n pada sara Oliseh
Akonimoogba egbe agbaboolu Super Eagles, Sunday Oliseh, si wa ni ile iwosan niluu Belgium nibi to ti n gba itoju lowo. Iroyin tuntun to te Olayemi Oniroyin lowo lati enu awon dokita isegun oyinbo ti n toju re fi ye ...
Read More »Oko ajagbe jale moto kekere lori ni Pota
Ijamba oko yii lo waye lale oni ni masose ilu Port Harcourt si Aba. Oko ajagbe kan lo yi le mo kekere kan lori eleyii ti eniyan wa ninu re.
Read More »Omidan to n wa ore tuntun fi leta ati Foto re ranse
Omidan Toyin lo kowe si wa wi pe oun fe ore, ko so wi pe oun wa oko o. Awon ore tuntun lo n fe, eni ti won yoo jo maa takuroso lasan. Awon to ba nife sii le fi ...
Read More »Leta ife jade lojo ti Olamide Orente se ojo-ibi alarinrin
Eni odun ba ba laye, e pe ko sope. Eni Edua oke ba dasi, e pe ko ke aleluya s’Olorun Oba. Ojo nla ni ojo oni je, ojo kejila osu kokanlan odun, ojo ti Omidan Awelewa Amoke, Oba Oge Eleyinju-ege ...
Read More »Gobe Sele Nigba Ti Omo Yari Wi Pe Oun o ni fohin
Yorùbá Dùn shared the following link and had this to say about it: Oloorun ni omo naa, ko fe ki won ba fohin re lero ni won ba mu lele fun un. Nje ohun to buru wa ninu igbese ti ...
Read More »Awon ologun yibon fun okan lara awon to pe fun Biafra ni Pota lonii
Leyin ti awon omo ologun yinbon pa okan lara awon oluwode ti won pe fun idasile Biafra, ibon tun ba okan lara won lonii niluu PORT HARCOURT.
Read More »Ilu Amerika gbalejo Goodluck Jonathan
Ilu Amerika ti gbalejo Aare ile Naijiria nigba kan ri, GOODLUCK JONATHAN si Challotsville to wa ni Virginia latari igbelaruge ijoba awarawa re ati gbigbe ijoba sile ni woorowo. Ogbeni Jonathan lo sokale siluu Amerika lojo aje ana. Lati Ọwọ ...
Read More »Lobatan: Won ti n ge tomato lori foonu chinco
Awon Yoruba ni ti ogun eni ba daniloju, eniyan fi i gbari ni. Ile ise China kan ti n se foonu, OUKITEL, ti kede wi pe, eni ba foju ana wo eegun, ebora nii boru won laso. Won ni to ...
Read More »