E gbo, taani igo rewa ju loju re? Se Toyin ni abi Muyiwa Ademola, abi Eniola nigo naa ye ju?
Read More »#Our5K ti da wahala sile lori ayelujara: Ile Igbimo Asofin ni wahala naa ti bere
#Our5K ti da wahala sile lori ayelujara: Ile Igbimo Asofin ni wahala naa ti bere Olayemi Olatilewa Lojo Wesde to koja yii nile igbimo asofin agba to kale siluu Abuja gbegi dina sisan owo egberun marun-un fun awon odo ile ...
Read More »Igbeyawo Asofin Moji Lawal niluu Eko leku!
Arabirin Moji Lawal, okan ninu awon omo ile igbimo asofin ipinle Eko segbeyawo alarinrin lopin ose to koja yii pelu oko re, John Paul to je onisowo pataki. Arabirin Moji, eni to je obirin akoko ti o ma soju ekun ...
Read More »E wo ohun ti Gomina Fayose n se laaarin oja
Gomina Ayodele Fayose da moto re duro loja Bisi to wa ni Ipinle Ekiti lati teti si edun okan iya arugbo yii nipa ohun ti won fe ki ijoba o se fun won. Gomina fara bale lati gbo gbogbo ohun ...
Read More »Igbe aye Oba Lamidi Olayiwola Atanda Adeyemi dun bi oyin
Laipe yii ni Oba Lamidi Adeyemi, Alaafin Oyo pe eni odun metadinlogorin. E le ka iroyin naa nibi: Lara awon foto ojo ibi baba mi-in to te wa lowo ni eyi ti baba ya pelu Olori Badirat Adeyemi, olori baba ...
Read More »Niluu Ilorin: “Awon osise mefa ti ku, awon kan wa nile iwosan”- Akowe egbe osise
Awon osise ajo olomi ti ipinle Kwara tu jade lojo Isegun to koja yii niluu Ilorin nigba ti won fi ehonu won han nipa owo osu won eleyii ti ijoba ipinle naa ko lati san lati inu osu keje seyin. ...
Read More »“Eyin ni agbara ati isegun mi l’Ojoosegun”: Ipinle Oyo gba leta Ajimobi
Olayemi Olatilewa Gomina ipinle Oyo, Abiola Ajimobi ti gbe sadankata fun awon eniyan ipinle Oyo fun atileyin ti won se fun un lati segun niwaju ile ejo to n risi awuyewuye eto idibo to waye lojo isegun to koja yii. ...
Read More »Won Fadi Omo Odun Meji Ya Niluu Abuja
Olayemi Olatilewa Omokunrin eni odun merindinlogun (16) kan ti lo foju ba ile ejo niluu Abuja leyin asemase pelu omobirin, eni odun meji (2) kan. Iroyin yii lo jade nigba ti olupejo, ogbeni Adama Musa, eni ti n soju ile ...
Read More »Owo te awon omo egbe okunkun niluu Ado-Ekiti
Olayemi Olatilewa Awon akekoo meji ile iwe gbogbonise ti ijoba apapo (Federal Polytechnic) to kale si Ado-Ekiti ati maanu kan ti n tu foonu se ni agbegbe naa ni won ti ko lo si iwaju ile ejo Majisireeti pelu esun ...
Read More »Ireti Odegbami ja sofo lati di aare FIFA agbaye
OlayemiOlatilewa Bi o tile je wi pe ajo ere boolu ile Naijiria ti n fenu so wi pe gbagbaagba ni awon wa leyin agbaboolu to gba boolu metalelogun (23) sawon ni akoko ti n gba boolu fun orileede Naijiria, ...
Read More »