Ní déédé agogo márùn-ún ìròlé àná ni ìjàmbá ńlá tí Ó tún jé mánigbàgbé fún orílè èdè Nìjíríà selè, nígbà tí Tánkà ńlá kan gbiná ní ojú pópó ònà tí ó wà láàrin ìlú Èkó si Ìbàdàn. Òpò àwon èèyàn ...
Read More »
Awoyemi Bamimore Comments Off on Tánkà tí Ó gbiná ní ànà tí Ó sì pa òpò èèyàn.
Ní déédé agogo márùn-ún ìròlé àná ni ìjàmbá ńlá tí Ó tún jé mánigbàgbé fún orílè èdè Nìjíríà selè, nígbà tí Tánkà ńlá kan gbiná ní ojú pópó ònà tí ó wà láàrin ìlú Èkó si Ìbàdàn. Òpò àwon èèyàn ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Nìjíríà ìgbà wo ni a ó gba òmínira.
Nìjíríà ńlé sunkún Àwon èèyàn ibè ò ye é rérìn-ín òfò Èrín òfò tí won rò pé ti ìdùnú ní se Nìjíríà ìlú tí òmínira rè ti di omi ìnirà Atún ti wálé Ojó wo ni àwa náà yóò gba ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on A DÚPẸ́ OOO GBOGBO ILẸ̀ WA TI DI IBOJÌ
A dúpẹ́ o Ikú ti di tiwa A dúpẹ́ o Àwọn èèyàn wa ò figi da mààlúù mọ́ AK 47 ni wọ́n ń lò A dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run Iṣẹ́ darandaran ti di iṣẹ́ dánràndáràn Èdùmàrè a dúpẹ́ o Ẹ dúró ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àbíkéyìn gbajúgbajà olórin tí a mò sí D’banj ni a gbó wípé Ó kú sí omi ní àná.
omokùnrin gbajúgbajà olórin tí a mò sí D’banj tí orúko omo náà ń jé Daniel ni a gbó wípé Ó kú sí omi ní àná tí a mò sí ojó kerìnlélógún osù kerin odún yii. Kí olúwa kí ó bá ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Rántí òla
Ohun tí a se lónìí Ìtàn ni b’ódòla Lisabi Agbongbo Àkàlà Fi ìwà akin gba gbogbo Ègbá kalè L’óko erú Olóòyó Ògèdèngbé ń be nínú ìwé ìtàn ìjeshà Asíwájú rere ní se Moremi obìnrinkùnrin n’ífè ńkó, a kò le gbàgbé ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ọ̀YÀYÀ (CHEERFULNESS)
Èro àlọ, Ẹ wá gbọ́, èrò àbọ̀, Ẹ wá tẹ́tí sími Oògùn ọlá tí mo ṣẹ̀ṣẹ̀ rí ní mo fẹ́ wí f’áyé Oògùn ọrọ̀ tí mo ṣẹ̀ṣẹ̀ gbà ní mo fẹ́ ròyìn Àtọjọ́ mo ti dáyé, Àtọjọ́ mo ti ń ...
Read More »ayangalu Comments Off on Oonirisa ni Ilu Oyibo: Abike jagaban, Esabod..
Awoyemi Bamimore Comments Off on Ìgbà èdá
Ìgbà kò lo bí òréré Ayé kò lo bí òpá ìbon, Ìgbà kan ńlo Ìgbà kan ńbo Kí elédùmarè jé kí á n’ígbà tó dára n’ílé ayé wa Ìgbà kan ni ogún náírà yí níyì púpò Sùgbón nísìnín Ó ti ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ahmed Musa ti mu Nìjíríà rérìn-ín ayò léèkan sí.
Gégé bí a ti mò wípé eré bóòlù ife àgbáyé ńlo lówó. Ahmed Musa tí Ó jé òkan Lára àwon omo agbábòòlú Nìjíríà ti gbá bóòlù méjì òtòtò wo ilé àwon alátakò won tí a mò sí ikò Iceland.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Òrìsà tí ń darí aféfé
Oya òpèré, Ekùn oko asè’ké Oya má bá mi jà Mi ò l’ówó aféfé ńlé Èmi ò rí eni tí yó ràgàn, ràgàn bí Oya ní òde ìpo Kò séni tí ó ràgàn ràgàn bí Oya lótù ifé Oya lo ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more