Ní’sàlé ni àwòrán ìsìnkú olóyè nínú ológun (Corporal) Odudu Davis tí ìbon pa nígbà tí osù kàrún di ogbòn ní inú odún yìí (30/5/2017)láti owó àwon olóòpá ojú omi (naval officer) nígbà tí àwon olóòpá àti àwon olóòpá ojú ...
Read More »A kú àyájó odún *Òmìnira* ti *orílè Èdè Nàìjíríà* ?? lónìí ooo.
A kú àyájó odún *Òmìnira* ti *orílè Èdè Nàìjíríà* ?? lónìí ooo. Èmí wa yóò se púpò rè láyé. E jòwó, e má sì gbàgbé láti se *ìwúre* fún orílè èdè *Nàìjíríà* ?? nítorí wí pé *”Ìròrùn igi ni ìròrùn ...
Read More »Arewa Toni
Oga Bello àti iyalode Binta Mogaji
Awon agba osere apanilerin meji
Read More »Ìyàwó mi dára sùgbón kò n’ìfé ìbálòpò léyìn ìgbeyàwó.
Ìyàwó mi dáa tí mo sì le pè ní aya rere sùgbón kìí gbà kí á bá ara wa lò nígbà tí ó ye, lóòtó aní omo okùnrin pèlú obìnrin. E jò ó kí ni mo le se? Mo ti ...
Read More »Kílódé tí àwon omoge fi n’ìfé àwon tí ó ti n’íyàwó.
E jòwó mo fé kí e dá mi lóhùn dáadáa. Gbogbo àwon Òré mi tí ó ti n’íyàwó n’ílé ni òpò obìnrin ń súré tè lé, tí ó sì jé wípé àwon àpón bí ti àwa yí obìnrin díè ni ...
Read More »Ìjàmbá ńlá okò kan tí ó ń jé Nissan Rogue selè ní òpópónà afárá 3rd mainland (3rd mainland bridge).
Okò tí ó ń jé Nissan Rogue àti Toyota Dyna kolu ara won ní òpópónà afárá 3rd mainland (3rd mainland bridge) ósì dà bí eni wípé okò Nissan Rogue náà wón ju iye tí won na lò. Àwon LRU ti ...
Read More »Mi ò ní dá DMs lóhùn mó – Davido so béè léyìn ìgbà tí ìkan nínú àwon olólùfé rè pa iró mo wípé òun ni ó kókó síde ìbáraenisòrò.
Ògá àkójopò HKN, Davido, tí ó pe ìkan lára àwon olólùfé rè obìnrin jáde, Sheilah Parker, tí ó gbe lo sí orí èro ayélujàra (snapchat ) láti p’aró mo wípé òun ni ó kókó síde ìbáraenisòrò pèlú arabìnrin náà. Olórin ...
Read More »Odómokùnrin odún mókàndílógún (19years) tí ósì jí olóyè kan gbé ni owó tè ní ìpínlè River.
Àwon òlùgbógunti Adigunjalè ti ìpín Okehi ní ìpínlè River ni owó won te òdómokùnrin kan tí ó ń jé Emeka Nwala tí ó jé odún méèdógbòn (25years) àti òdómokùnrin Otamasiri Onyesu tí ó jé odún mókàndílógún. Tí won sì fi ...
Read More »Àwòrán tuntun tokotayà tí won sèsè fé ara won léyìn tí won ti wà gégé bí Òré tímótímó.
Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó olùgbá bóòlù aláwòn ní Brooklyn, Quincy Acy àti àfésónà rè, Jessica Fuenten tí ó sèsè gbòde kan léyìn ìgbà tí inú arewà ìyàwó àfésónà sì ń dùn, so wípé àwon bèrè gégé bíi ...
Read More »