A ku deede asiko yii o gbogbo olugbe aafin ilumoye, eeto yin eeto wa owe l’esin oro ni o tun wole de weere yi ooo, e wa nkan fidile ki a dijo gbadun eeto ti toni. Siwaju ki eeto o ...
Read More »
ayangalu Comments Off on Eeto Owe L’esin Oro
A ku deede asiko yii o gbogbo olugbe aafin ilumoye, eeto yin eeto wa owe l’esin oro ni o tun wole de weere yi ooo, e wa nkan fidile ki a dijo gbadun eeto ti toni. Siwaju ki eeto o ...
Read More »E dakun, e bawa fun arakunrin yii ni oruko kan ?
Read More »ayangalu Comments Off on Eto Olobe Loloko: Sokoyokoto !
Adupe lowo eledua, oba alaanu, olorun to ohunkohun ko sooro se fun lati se,Adupe lowo olorun ti o tun ka wa ye ni ojo toni, a ki gbogbo wa ku bi oju ojo ti ri oo, nigiriya a kuku de’run ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ayo Ab’ara Bintin !
Ope ni fun Olorun nitori ti o seun ti anu Re duro laelae. Mo layo lati so fun yin wipe Eledua fi Omo Tuntun Jojolo da ebi kan pataki ninu ilu yi lola. Tii se ebi Alhaja wa Adetunji Adenike ...
Read More »ayangalu Comments Off on ‘Yee! Yee!! Ni gbogbo n ke’
Basẹ ba mumi Omi a tan ninu asẹ, Bígèrè ba mumi Omi a tan ninu ìgèrè, ko tan ko tan lajá á lami; Ó tán n bí ò tàn? A ráta, a rata, ata kan ojú, ata n tani bi ...
Read More »ayangalu Comments Off on Fi Ti Okunrin Akonimogba(coach) Egbe Agbabolu Lesesita (Leicester-club) yi se arikogbon
orewa! iwo nan ma ro ararepin, fi ti okunrin akonimogba(coach) egbe agbabolu lesesita (Leicester-club) yi se arikogbon, toripe ORI TI YO DE ADE BOTI WU KORI KONI SE ALAIDE, atipe ILE ANU OLOHUN KI SU fun idi-eyi maso ireti nu ...
Read More »ayangalu Comments Off on E Ase iwure yi ooo
Huunn Mose kabiyesi fun oba mi. Oba ajidara Oba toje dada owo e lowo. Iyi ti o da no nbe lowo eledumare Mo wa nbe o. Eledumare Jo o ma fiwa dara buruku o. Ma fun wa ni.omo abami eda. Oooo ...
Read More »ayangalu Comments Off on Gbolun kan fun baba oni bata yi
Eku dede asiko yi ooooo. E jo eyin omo ilu mi
Read More »ayangalu Comments Off on Oruko Kan Fun Iya omode yii ?
Eyin Eniyan mi Eje Kia Rerin die. Oruko kan fun iya omode yii ?
Read More »ayangalu Comments Off on Oro ton’lo Lowo bayi: E wo tomato timo ra ni 500 naira
Eku Dede asiko yio eyin eniyan Atata tin GBE inu ilu Yoruba Atata, oro tonlo Lowo bayi ni mo muwa oro elo obe to won gogo yi ma ni mofe kia soro Lorie o. E wo tomato timo ra ni ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more