Home / Tag Archives: oodua news (page 2)

Tag Archives: oodua news

alafin

Eyi ni Oruko oye awon oba Alade ni Ile Oodua/Yoruba #tradition #yoruba #king #oba

Ewo ninu won ni oba ilu tiyin Ooni of Ile-Ife Alaafin of Oyo Awujale of Ijebuland Alake of Egbaland Olowu of Owu Oluwo of Iwo Olubadan of Ibadan Soun of Ogbomoso Oba of Benin Owa Obokun of Ijesha Osemawe of ...

Read More »
Shehu

PDP Vs APC Social media information war continues: Garba Shehu Denies Buying $800k

*Threatens To Sue PDP Twitter Admin Presidential representative Malam Garba Shehu said the PDP lied in asserting that he purchased USD 800,000 from the Central Bank of Nigeria at 185 naira, including that he will resign from his position the ...

Read More »
bitie

Idi pataki meta ti ko fi ye ka maa fi ehin je eekanna

1. Ehin le yingin tabi ki die kan lara ehin wa: Nigba mi-in ti a ba n gbiyanju lati fi ehin ge eekanna wa, ehin wa le lura won lojiji, eleyii si le fa ki ehin yingin legbe kan tabi ...

Read More »
maduaeke ati dele

Dele Momodu se afihan Madueke nigba keji

Fun awon ti ko mo, Dele Momodu ni oniroyin akoko to koko se afihan foto Diezani Alison-Madueke. Eleyii to ya nigba to se abewo si minisita fun epo robi nigba kan ri ni ilu London.Oga Dele Momodu ti pada se ...

Read More »
court

“Iyawo mi n yale, o tun bimo ale fun mi”: Alabi yari ni kootu Ikorodu

Orisun   Ogbeni Alabi Rasheed, eni odun mejidinlaadota (48) ti gbe iyawo re, Sherifat, lo si ile ejo lati tu yigi igbeyawo odun mewaa to wa laaarin won ka lOjobo ose to koja yii. Gege bi alaye Alabi ni Ikorodu ...

Read More »
buhai iranu

Baalu Aare Buhar ti bale niluu Iran

Aare Muhammadu Buhari ti bale ni Tehran to wa ni orileede Iran nibi ti yoo ti maa joko se ipade eleeketa iru e ti egbe awon orileede ti n gbe epo robi jade fun awon orileede agbaye.

Read More »