Senator Ben Murray-Bruce, his wife and children attended the BET awards last night.
Read More »
		Lolade Comments Off on Ben Murray-bruce And His Family spotted At The BET Awards (Photos)
Senator Ben Murray-Bruce, his wife and children attended the BET awards last night.
Read More »ayangalu Comments Off on Ilé ejó gíga jù dá asòfin ìpínlè Taraba dúró, tí orúko rè ńjé Sani Danladi
Won pàse fun kí ó dá owó osù àti àláwánsì tí ó gbà. Ilé ejó gíga jù ti pàse fún asòfin tí ó ń sojú ilé asòfin àgbà àríwá ti ìpínlè Taraba sani Abubakar Danladi láti fi ipò náà sílè ...
Read More »ayangalu Comments Off on Àwon Agbófinró ìpínlè Èkó so ònà tuntun tí àwon gbómogbómo ńgbà jínigbe.
Àwon Agbófinró ìpínlè Èkó so ònà tuntun míràn tí àwon gbómogbómo ńgbà jínigbe. Ní ìsàlè ni òrò tí agbenuso àwon Agbófinró ìpínlè Èkó, SP Dolapo Badmos so. “E jò ó tí enikéni bá fi káàdì ìpè ráńsé sí yín tí ...
Read More »BalogunAdesina Comments Off on Syrian War Report – June 23, 2017: Army Regaining More Ground Near Palmyra
The Syrian Arab Army (SAA), the National Defense Forces (NDF) and other pro-government factions have further advanced against ISIS and US-backed militants in the province of Homs. On Thursday, government troops captured Tal Ghurab northwest of the US garrison of ...
Read More »Lolade Comments Off on Video: Nigerian mathematician Builds Flying F-35D prototype (Flying Drone)
Time to invest heavily in this man.
Read More »ayangalu Comments Off on Àwon ológun yín ìbon lu omokùnrin odún márùn-ún ní Kaduna nígbà tí won ń ké ìrora won ní rowérosè ..
Gégé bí omo oòduà rere se so, omokùnrin odún márùn-ún tí orúko rè ńjé Hussein Mustapha ni àwon ológun yin ìbon lu nígbà tí won ń ké ìrora (rally) ní Kaduna láti fi àmì sí Qusday ní àgbáyé láti gba ...
Read More »ayangalu Comments Off on Àwòrán; Toke Makinwa jáde ní àrà òtò ní orílè èdè South Africa láti pàdé SA OAP àti àwon t’ókun lórí àjò SA tí ó ń bò lónà.
Toke Makinwa sèsè dé sí orílè èdè South Africa láìpé yí gégé bí ó se ń rìn káàkiri àgbáyé láti di gbajúgbajà ònkòwé. Ìmúra rè yanilénu nígbà tí ó wo aso aláwò pupa férééfé (pink Gert Johan) àti bàtà ...
Read More »ayangalu Comments Off on Alaafin Of Oyo Declares fake Ifa Priests Wanted, Sues Them For Giving Oyinbo Titles
PUBLIC NOTICE UNSCRUPLOUS ACTIVITIES OF SOME IFA PRIESTS IN OYO Recent events in Oyo and other parts of the world concerning the activities of some Ifa priests from IJO IFA ADIMULA TEMPLE, BARA in Oyo town, wherein unsuspecting foreigners who ...
Read More »ayangalu Comments Off on Gómìnà Nyesom Wike dá òkan lára àwon Konmisôna rè dúró.
Gómìnà ìjoba ìpínlè River, Nyesom Wike ní òwúrò yí dá Konmisôna isé dúró ní ìpínlè rè tí orúko rè ńjé Bathuel Harrison (àwòrán eni tí ó wo jákèètì). Nínú òrò tí olùrànlówó pàtàkì rè so lórí ìtànná ohun Ìgbéròyìn jáde ...
Read More »ayangalu Comments Off on Díè nínú ìsesí láti òdò Dino Melaye lórí ìròyìn èrò rè tí a se ìrántí láti ìgbìmò asòfin àgbà.
Ní àná, ìgbìmò tí ó ń darí ètò ìdìbò (INEC) gba àpò méfà tí ó kún fún ìbowólù àwon tí ó tó láti dìbò ní agbègbè Eokun ìwò oòrùn ní ilè Kogi, tí ó ń bèèrè fún ìrántí Dino Maleye ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more