Titi Masha ni yii, okan ninu awon orekelewa obirin ti K1 de Ultimate fi n segbaladun niyewu. Titi rewa pupo lobirin, oju re ri rekete bi ojo, ibadi aran ti n danilorun nigba gbogbo. [Olayemi, ara n fu mi si o]
Gege bi iwadii Olayemi Oniroyin, Titi wa lara awon iyawo oba Fuji to wa lojuopon bayii, obirin naa si ni alase ati oludari Fathia Fabrics to wa ni Surulere eleyii to kale silu Eko Oba Akinolu.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more










