Looking at the Odù, Ọ̀bàrà Méjì cast for today’s Ọ̀sẹ̀ Ifá, I quickly remember the song of the legend, late Hubert Ogunde from the album, “Onímọ́tò” where he sang as follows :-
Asúrétete ò màní kọ́já ilé
Arìngbẹ̀rẹ̀gbẹ̀rẹ̀ ò màní sọnù sọ́nà
Impatient fast runner will not pass home
Slow walker will not get lost on the road
Now let’s bring it home. Why are we always in a hurry? Just listen to the stanza.
Ìkánjú ò ṣe jayé
Wàràwàrà ò ṣe jù s’ápò
Gbogbo ohun t’Ọlọ́run bá fún wa làágbà
Adífá fún Èyí t’ó ń rìn ọmọ Èjìọ̀bàrà
Èròpo èrò ọ̀fà bó pẹ́ títí èèyàn t’ó tí ń rìn a dé’lé mọrẹ
Hastening doesn’t guarantee life enjoyment
Dangerous hurrying is not habitable
Whatever the Almighty Creator gives us should be accepted in good faith
Cast divination for a walker, the child of Ọ̀bàrà Méjì
People of Òpo and Ọ̀fà ( representing the world), let it be known that no matter how long it takes one to walk, one must surely get to one’s destination (home).
My people, EASY DOES IT.
Ẹni t’óbá l’étí k’ógbọ́
Those who have ears let them hear
Stay blessed
From Araba of Oworonsoki land Lagos Nigeria
Tagged with: ODU IFA