Paul Okoye tí a mò sí Rude boy ni ó pín àwòrán tí ó rewà yí nígbà tí ó ń lo àsìkò pàtàkì pèlú àwon ìbejì rè Nadia àti Nathan seré èyí tí ó pín sí orí èro ayélujára (instagram)..
Read More »
Awoyemi Bamimore Comments Off on Paul Okoye níbi tí ó ti ń bá àwon ìbejì rè Nadia àti Nathan seré .
Paul Okoye tí a mò sí Rude boy ni ó pín àwòrán tí ó rewà yí nígbà tí ó ń lo àsìkò pàtàkì pèlú àwon ìbejì rè Nadia àti Nathan seré èyí tí ó pín sí orí èro ayélujára (instagram)..
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Kemi Olunloyo so báyìí wípé! Àwòkóse burúkú gbáà ni Linda Ikeji àtiwípé òun ni àwòkóse there.
Kemi Olunloyo so báyìí wípé! Àwòkóse burúkú gbáà ni Linda Ikeji àtiwípé òun ni àwòkóse rere.OK olunloyo so òpòlopò àsírí nípa oyún inú Linda Ikeji àti nípa ara rè pàápàá. Àtiwípé Linda Ikeji ti kó bá òpòlopò òdóbínrin.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Sùúrù lógbà.
Ìsé kìí se ohun àmúseré Ìyà kìí se ohun àmúsàwàdà Ebi ń pamí kìí mérìń p’ani Sebí ebi kìí w’onú Kí òrò míràn wòó Ojú tí ń kúkú pón isin Kìí se àpón ku Bí kòse àpónlà Bówù kópé títí ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on A o ni ri ogun aisan
A o ni r’ogun aisan! Ifa ni: Pere ni tewe iyeye, aloye ni ti peregun; Piri l’eye olongo n ji; A kii b’okunrun eye lori ite; Gege lowu alantakun n fuye; Ota kii ku, ota kii run; Koko lara ota ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àfi kí á ma dúpé.
Àfi kí á ma dúpé . Ìwo tí o wà láyé Tí ò ń jeun àsìkò Tí o tún ń wo aso àsìkò Ó tó kí olúwa rè sopé Olúwa tún wá ba o se é Ó tún fún o ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on ORIKI ILORIN Ilorin afonja.
ORIKI ILORIN Ilorin afonja enudunjuyo Ilu to jinna s’ina To sunmon alujana bi aresepa Ilu tobi to yen,won o leegun rara Esin l’egungun ile baba won Akewugberu ni won A s’adura gbore Aji fi kalamu da won lekun arise kondu ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on ORÍKÌ OFA
Otunba Ikanni: Iyeru okin olofa mojo, Omo olalomi, omo a basu Jo o ko Omo la a re, bu u re, Okan o gbodo jukan, Bokan bajukan Nile olofa mojo, Ogun Oba ni i kowon ni roro, IJA kan IJA ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Oríkì Òsun
Òsun sègèsé olórìyà iyùn Awede kí ó tó we’mo Òsun eléyinjú àánú Igbómolè obìnrin Òsaàyò m’olè Òmómó t’enu m’olè Ayaba bìnrin òtòrò èfòn n’ílé ìyá olúgbón Won kò gbodò m’awo Ìran Arèsà Won kò gbodò m’orò Olúwa mi ló m’orò ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on SANGO, kABIYESI O!!! LALU OBA KOSO ORIKI SANGO.
Olúkòso! Atu wón ka níbi wón gbé ‘ndáná iró. A lé Babaláwo máa dúró kó Ifá, À ti lójò àti lérùn, Kò séni tí Sàngó kò lè pa. À f’eni tí kogílá kolù, À f’eni tí Esù ‘nse, Ló máa ...
Read More »ESE KINNI_ Dìde Èyin Ará Waká jé ipe Nàijíríà K’à fife sin ‘lè wá Pel’ókun àt’sígbàgbó Kìse Àwon Àkoni wá, kò máse já s’ásán K’à sin t’òkan tará Ilé t’ómìnira,àt’àláfíà So d’òkan. *ESE KEJI* Olórun Elédàá Tó ipa Ònà wa ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more