Kété tí wọ́n bá ṣí iléẹ̀kọ́ padà ní ìdánwò WASSCE yóò bẹ̀rẹ̀…Àjọ WAEC Ìgbà lonígbà ń kà, àkókò ò wojú ẹnikẹ́ni àyàfi èèyàn tó bá setán àti ṣàmúló rẹ̀ lójú ọjọ́.Bí a bá wo ọṣẹ́ tí àrùn apinni léèmí Kòrónáfairọ̀ọ̀sì ...
Read More »Àwo̩n S̩ó̩ò̩sì bè̩rè̩ ìjó̩sìn l’Abuja lónìí
Àwo̩n S̩ó̩ò̩sì bè̩rè̩ ìjó̩sì l’Abuja lónìíYínká Àlàbí O le ni osu meji bayii ti ijoba apapo ti fofin de Soosi ati Mosalasi. Ijoba ni ki onikaluku maa josin ni ile won, ijoba ni ko si ibi ti Olorun ko si ...
Read More »Odún dé, Gbogbo Irúnmolè e gbé ire wá
Our World Ifa festival has come, all divinities, we request that goodness is brought to us all. Just listen to Òsé Orógbe as follows:- Eésan ò sé gbá lójúÀkeèkèé ò se é dìníbòAdífá fún Odún tíí se Yèyé ObaÒsé tééré ...
Read More »KỌ́JỌ́DÁ 10062: Odún Dé Omo Eríwo…
Happy world Ifa Festival to all the traditionalist around the globe.Irinwó imolè, igba imolè, Olódùmarè yóò gba gbogbo irè wa, àmódùn á jù báyìí lo. We shall all witness more of it on earth. Ajoke Olóbì❣️❣️❣️❣️❣️ Kojoda 10,062
Read More »Auxiliary, ata dùǹdú rẹ̀ ń fínmú — Ìjọba Ọ̀yọ́ dúnkookò
Auxiliary, ata dùǹdú rẹ̀ ń fínmú — Ìjọba Ọ̀yọ́ dúnkookò Ó dà bí ẹni pé orí tí yóó súpó, kìí jẹ́ kí ti ọlọ́kùnrùn ó yè ni ọ̀rọ̀ fẹ́ dà báyìí fún asáájú ìgbìmọ̀ tó ń ṣe àkóso gárèjì ọkọ̀ ...
Read More »O̩ló̩run sì máa gbè̩san ikú bàbá mi – O̩mo̩ o̩ko̩ olóyún
Olorun si maa gbesan iku baba mi – Omo ojo OloyunOjo ketalelogun osu kin-in-ni odun yii ni awon adiha-Moran kan lo yinbon pa Alhaji Fatai Yusuf ti gbogbo eniyan mo si oko oloyun. Lati igba naa ni awon olopaa ti ...
Read More »Covid-19 ló sàkóbá fún isé̩ e̩gbè̩rùn kan, ìjo̩ba ìbíle̩ kan – Festus Keyamu
Covid-19 ló sàkóbá fún isé̩ e̩gbè̩rùn kan, ìjo̩ba ìbíle̩ kan – Festus KeyamuYínká Àlàbí Agbejoro agba to n ja fun eto omoniyan to tun je minisita eto ise fun ipinle, Festus Keyamu lo n salaye fun awon oniroyin nipa aseyori ...
Read More »Àjo̩ NCDC mú mé̩ta nínú oògùn ìbíle̩ fún ìwòsàn covid-19
Àjo̩ NCDC mú mé̩ta nínú oògùn ìbíle̩ fún ìwòsàn covid-19Yínká Àlàbí Ajakale arun ti gbogbo eniyan ro pe ko ni pe fi orileede yii sile, lo ti ko ti ko lo mo yii. Eyi lo wa bere si ni ko ...
Read More »Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ máa wo̩lé láìpé̩
Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ máa wo̩lé láìpé̩ Gbogbo igbiyanju ni awon ajo eto eko ti wa ninu awon ajo NCDC n se bayii lati le je ki awon akekoo wole eko won. Oro arun coronavirus yii ti su gbogbo aye. Ile ti ...
Read More »Èsì àyẹ̀wò tuntun Nàìjíríà fihàn pé “313” èèyàn ti gbàlejò Kofi 19 …àjọ NCDC
Èsì àyẹ̀wò tuntun Nàìjíríà fihàn pé “313” èèyàn ti gbàlejò Kofi 19 …àjọ NCDC À fi kí á bẹ Ọlọ́run kó bá wa dásí ọ̀rọ̀ àjàkálẹ̀ àrùn ajániláyà pàtì yìí, bí àwọn tó ní kòrónáfairọ̀ọ̀sì ní Nàìjíríà ti ń peléke ...
Read More »