Chimamanda Ngozi Adichie ni won bí ní ojó keèdógún osù kesàn-án odún 1977 (15/09/1977), jé olùkòwé ní orílè èdè Nìjíríà, ó n ko ìtàn kékeré àti èyí tí ó pò, ó n ko èyí tí ó jé ìtàn ojú gbangban ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
Awoyemi Bamimore Comments Off on Chimamanda Adichie se ayeye ojó-ìbí rè nígbà tí ó pé omo odún mókànlélógójì (41) lóòní.
Chimamanda Ngozi Adichie ni won bí ní ojó keèdógún osù kesàn-án odún 1977 (15/09/1977), jé olùkòwé ní orílè èdè Nìjíríà, ó n ko ìtàn kékeré àti èyí tí ó pò, ó n ko èyí tí ó jé ìtàn ojú gbangban ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwòrán àwon tokotayà jí ó tó di ojó ìgbéyàwó won; ìyàwó fi èyìn rè han oko láti yè é wó .
Àwòrán àwon tokotayà jí ó tó di ojó ìgbéyàwó won; ìyàwó fi èyìn rè han oko láti yè é wó . Ìyàwó tí ó rewà fé kí oko rè mo ohun tí ó n kó owó lé lórí, àti wípé ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Owolabi Awodotun Aworeni omo Àràbà télè, Araba Adisa Aworeni, di Àràbà Àgbáyé.
Gbogbo onísèsi àgbáyé ti darapò láti fi Omo Ekùn je Àràbà káàkiri àgbáyé. Lóòótó òpò ni yóò ma rò wípé báwo ni ó se tún jé wípé omo Àràbà tí ó sísè náà ni ó tún jé, súgbón eni orí ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Miracle Ikechukwu dé ìlú Imo léyìn ìsinmi olójó gbooro, tí ó pín àwòrán
Miracle Ikechukwu dé ìlú Imo léyìn ìsinmi olójó gbooro, tí ó pín àwòrán . Gbajúgbajà Bbnaija tí a mò sí Miracle tí ó lo fún ìsinmi olójó gbooro ti padà sí orílè èdè Nìjíríà gégé bí ó se kakè sí ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Reekado Banks gba Larry Ekundayo l’álejò ní ilé rè.
Omo ikò ti egbé olórin ìgbàlódé tí a mò sí Mavin, Reekado Banks ti gba okùnrin a gba àmì èye ní àlejò ní ilé rè, àwon méjèjì pín fídíò náà sí orí èro ayélujára. E wo àwòrán won ní ìsàlè.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Arákùnrin kan ni ó fi ìtò ara rè wè látàrí àpòjù ìmukúmu.
Arákùnrin kan ni ó fi ìtò ara rè wè látàrí àpòjù ìmukúmu. Arákùnrin kan ni a rí ní Ayobo, agbègbè kan ní ìpínlè Èkó tí ó n fi ìtò ara rè wè tí ó rò wípé omi ni látàrí ìmukúmu ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ayé Kareem ti yí padà di òtun láti ìgbà tí ó ti ya àwòrán Ààre Macron- Alákoso rè ló so béè.
Óríre míràn ti to omo kékeré, omo odún mókànlá tí a mò sí Kareem Waris Olamilekan tí olórun fún ní èbùn kí ó ma ta nkan, ó ti ya ààre ilè Faransé tí a mò sí Ààre Emmanuel Macron, nígbà ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ìròyìn Òrofó ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.
1 Ààrẹ Buhari yóò dé lónìí láti orílẹ̀ èdè China. 2 Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọ̀ṣínbàjò gba àlejò àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọn gbé igbá orókè nínú ìdíje ìmọ̀ ẹ̀rọ ìgbàlódé. 3 Àwọn oníròyìn ń fi ìròyìn burúkú bá ìjọba Buhari ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Arábìnrin kan ni ó bí ìbeta léyìn odún métàdínlógún tí ó tí se ìgbéyàwó.
Arábìnrin kan ni ó gbe lo sí orí èro ayélujára tí a mo sí facebook láti lo pín ìròyìn ayò wípé òhun bí ìbeta láti bí odún métàdínlógún sèyìn. Ó ko síbè wípé… ” èyin abiyamo mi ò le mú ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwon omo egbé APC ti Gúúsù Oyo ti jóòkó ìgbìmò – Abiola Ajimobi lo kí Alaafin Oyo.
Gómìnà ìpínlè Oyo , Abiola Ajimobi , tí ó ti fi okàn àwon omo egbé APC ti ìpínlè Oyo lókàn balè wípé omo egbé àwon ló ma wolé ní ibi ìdìbò tí ó n bò lónà ní odún 2019, àti ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more