Igbákejì gómìnà Òǹdó Agboola Ajayi tilé APC bọ́sí yẹ̀wù PDP Ó dà bíi pé , ẹ kú àtilé bọ́ọ́lé ló kù báyìí, tí àwa òlùdìbò yóó ma kí àwọn olóṣèlú wọ̀nyí lásìkò yìí, tí wọ́n kàn ń múwa ṣeré nínú ...
Read More »Kíní orúkọ tí wọn npè Ìsọ yìí ní èdè ìlú ti’yin?
Aku ataro óò Adé kú ọjọ yìí Kíní orúkọ tí wọn npè Ìsọ yìí ní èdè ìlú ti’yin náà?????? #iya lájé
Read More »Eṣọ́ àjọ FRSC mẹ́ta tí ààrá sán pa gbọdọ̀ ṣ’ètùtù – Ẹlẹ́buùbọn
Eṣọ́ àjọ FRSC mẹ́ta tí ààrá sán pa gbọdọ̀ ṣ’ètùtù – Ẹlẹ́buùbọn Ṣé ọlọ́tọ̀ ní t’óun ọ̀tọ̀, a díá fún òkú tó kú ńlé, tí wọ́n sin s’óko.Àgbà Imọlẹ̀ kan nlẹ yìí ti fèsì sí ìṣẹ̀lẹ̀ ààrá tó sán láìpẹ́ ...
Read More »Fidio: Ipinle Eko
Ilé ẹjọ́ kòtẹ́mílọ́rùn yọ alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC Adams Oshiomhole nípò
Ilé ẹjọ́ kòtẹ́mílọ́rùn yọ alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC Adams Oshiomhole nípò– Ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn ti ilú Àbújá ti yẹ àga mọ́ alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC, Adams Oshiomhole nídìí Ìgbìmọ̀ ẹlẹ́ni mẹ́tà ti adájọ́ Eunice Onyemanam sójú fún ni wọ́n fẹnu ...
Read More »L’ẹ́gbẹ́ òṣèlú APC; alága méjì lójijì lalẹ̀ hù—- Ajimobi àti Victor Giadom
L’ẹ́gbẹ́ òṣèlú APC; alága méjì lójijì lalẹ̀ hù—- Ajimobi àti Victor Giadom Àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní bí ọ̀rọ̀ ńlá kò bá tí ì tán, èèyàn ńlá kò níí sinmi àròyé.Sinimọ́ oríta sì ń tẹ̀síwájú pẹ̀lú ọ̀rọ̀ tó jẹ mọ́ ...
Read More »O̩jó̩ ìdìbò kò sún síwájú ní Edo – INEC
O̩jó̩ ìdìbò kò sún síwájú ní Edo – INEC Alaga patapata fun eto idibo ni orileede yii, Ojogbon Mahmood Yakubu lo n salaye yii ni ilu Abuja.O ni pelu rogbodiyan to n lo ni ipinle Edo, awon kan ti n ...
Read More »Èmi ò ní fàá ká jáa pè̩lú Tinubu – Aregbesola
Èmi ò ní fàá ká jáa pè̩lú Tinubu – Aregbesola Gomina tele ri ni ipinle Osun, Ogbeni Rauf Aregbesola ni o tinsalaye ni aimoye igba pe oun ko ni Ojogbon kankan pelu Asiwaju Bola Tinubu.O ni “ogede ko le wo ...
Read More »Bàbá mi máa jáwé olúborí ipò Ààre̩ ló̩dún 2023 – Adamu Atiku
Bàbá mi máa jáwé olúborí ipò Ààre̩ ló̩dún 2023 – Adamu Atiku Alhaji Atiku Abubakar ni igbakeji Aare tele ri ni orileede yii. Oun ni igbakeji Oloye Olusegun Obasanjo nigba naa.Atiku dije du ipo Aare ni odun 1993 ni eyi ...
Read More »Orisirisi: Àwọn àǹjàǹnú ń gbowó oṣù l’ájọ Sùbẹ́ẹ̀bù Kwara- EFCC
Àwọn àǹjàǹnú ń gbowó oṣù l’ájọ Sùbẹ́ẹ̀bù Kwara- EFCC Àjọ tó ń gbógun ti ìwà jẹgúdújẹrá lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà EFCC sọ pé àṣírí àwọn ayédèrú òṣìṣẹ́ ẹgbẹ̀rún kan àjọ tó ń ṣàkóso ètò ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ nípìńlẹ̀ Kwara ti tú sí àwọn ...
Read More »