Ìwà Pẹ̀lẹ́(Good Character) is ultimately the basis of moral conduct in Yorùbá Culture and a core defining attribute of an Ọmọlúwàbí. Also, One of the basic concepts of Indigenous Tradition, as the welfare and development in life.
Read More »Àríwá Nàìjíríà, Ẹ Sọ Ẹran Jọ̀bọ̀jọ̀bọ̀ Nù Bí Ẹ Ṣe Yọ Sanusi – Soyinka
Ọ̀jọ̀gbọ́n Wọlé Soyinka ti bu ẹnu àtẹ́ lu bí Ìjọba ìpínlẹ̀ Kano, lábẹ́ ìsàkóso Gómìnà Abdullahi Umar Ganduje, lórí bó ṣe rọ Lamido Sanusi lóyè, gẹ́gẹ́ bí Emir ìlú Kano.
Read More »Osinbajo wọ́gilé ìrìn-àjò rẹ̀ lẹ́yìn tí ọ̀kan lára ẹ̀ṣọ́ rẹ̀ kú lọ́nà pápákọ̀ òfurufú
Osinbajo wọ́gilé ìrìn-àjò rẹ̀ lẹ́yìn tí ọ̀kan lára ẹ̀ṣọ́ rẹ̀ kú lọ́nà pápákọ̀ òfurufú Ọ̀kan lára àwọn ẹ̀ṣọ́ ìgbákejì Ààrẹ, Ọ̀jọ̀gbọ́n Yemi Osinbajo sàgbákò ikú ójijì nínú ìjàmbá alùpùpù lọ́jọ́ Ẹtì. Ali Gómìnà, tó jẹ́ ọlọ́pàá rìpẹ́tọ̀ gbẹ́mì ín mì ...
Read More »Fayemi, ilẹ̀ Oòduà (Yorùbá) kìí ṣe Kano tí wọn ti ń yọ Emir lórí oyè… Alaafin
Àwọn ọmọ Nàìjíríà lórí ojú òpó ìkànsíraẹni Twitter ti dásí ọ̀rọ̀ láàrin Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ekiti, Kayode Fayemi àti àwọn ọba ní ìpínlẹ̀ náà. Èyí kò sẹ́yìn lẹ́tà tó jáde lórí ẹ̀rọ ayélujára níbi tí Aláàfin Ọ̀yọ́, Ọba Lamidi Olayiwola Adeyemi ...
Read More »Coronavirus: 4 Ways To Properly Sanitize And Clean Your Smartphones
The coronavirus is here and it's not showing any sign of going a way soon. One of the best method of preventing the virus is by washing our hands with soap and keep it off our face.
Read More »The Nigerian health minister, according to some reports, just announced that the second coronavirus case in Nigeria has tested negative.
The Nigerian health minister, according to some reports, just announced that the second coronavirus case in Nigeria has tested negative.
Read More »Òhun tí Ọlọ́run ṣe fúnmi ju n tó tọ́ sí mi lọ— Ọbasanjọ
Òhun tí Ọlọ́run ṣe fúnmi ju n tó tọ́ sí mi lọ— Ọbasanjọ Olóyè Ọbasanjọ, gẹ́gẹ́ bí ara ètò fún ayẹyẹ ọjọ́ ìbí ọdún kẹtàlélọ́gọ́rin rẹ̀ léwájú àwọn èèkàn lọ síbi àpèjẹ pàtàkì kan fún àwọn àlejò gbogbo. Olóyè Ọbasanjọ ...
Read More »Gómìnà Kaduna, El-Rufai fi ipò kejì dá Sanusi lọlá láàrin ọjọ́ méjì
Wọ́n fikún un pé àwọn gbé ìgbésẹ̀ náà nítorí wọ́n mọ pé ìpínlẹ̀ Kaduna yóó rí ohun ribiribi kọ́ lára ọgbọ́n tí Sanusi ní àti òye rẹ̀ nípa ètò ọrọ̀ ajé.
Read More »I’m An Oodua Boy, Anthony Oluwafemi Olaseni Joshua, Tells Queen Elizabeth
Anthony Joshua has extolled the virtues of his Nigerian heritage while addressing members of the royal family.
Read More »Nigerian Army Suffers Heavy Losses In Failed Attack On Isis Cells In Borno – Video
The Nigerian Armed Forces (NAF) have suffered heavy losses in a recent attack on the remaining ISIS cells in the northeastern province of Borno.
Read More »