Goodluck Ebele Jonathan se ayeye odún mókànlélógóta (61) ojó ìbí rè ní èní.
Goodluck Ebele Azikiwe Jonathan GCFR GCON tí won bí ní ogún’jó osù Belu ní odún 1957, tí ó jé olósèlú ní orílè èdè Nìjíríà tí ó sì sin ìlú gégé bíi Ààre orílè èdè Nìjíríà láti odún 2010-2015. Kí ó ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more











