Home / Art / Àṣà Oòduà / Ògbóntarìgì Adigunjalè tí ó n dà àwon ará Delta láàmú ni owó ti tè.

Ògbóntarìgì Adigunjalè tí ó n dà àwon ará Delta láàmú ni owó ti tè.

Ògbóntarìgì Adigunjalè tí ó n dà àwon ará Delta láàmú ni owó ti tè.
Ògbólògbó adigunjalè ní òrò won ti já sí òfo látàrí àì jé kí àwon èèyàn ní ìfòkànbalè ní ìpínlè Delta.
Àwon adigunjalè méjì tí ó n da àwon ará ìlú Igbodo ti ìjoba ìbílè ti Gúúsú Ika àti agbègbè rè láàmú ní àwon olùdábòbò ìjoba ti pa.
A gbó wípé àwon ìgárá Olósà pàdé ikú ní òwúrò ojó Etì (Friday) nígbà tí owó àwon olópàá àti figilanté bà wón.
Àwon afurasí nígbà tí won fi èsùn kàn wón nígbà tí won n gbìyànjú àti ja okò nlá tí ó kó síméntì ló lè.
A gbó wípé olórí àwon olósà yí tí a mò sí “CHOPPING” kí ó tó di wípé ó kú ni ó tí n da àwon arìn rìn àjò láàmú tí àwon ará ìlú kò sì le wo, nígbà tí ó n wo ilé lo jà wón lólè tí ó sì tún gba àwon ohun ìní won.
Ìròyìn ikú rè àti ti àwon akegbé rè dún mó àwon ará ìlú nínú púpò jú, tí won sì kó àwon tí ó kù sí àgó olópàá.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti