Gómìnà ìpínlè Osun tí a mò sí Aregbesola ti kéde oludé fún gbogbo òsìsé ìjoba fún odún ìsèsí tí yóò wáyé ní òla ogúnjó osù kejo odún 2018.Asèyí se àmódún, ìsèsi á gbè wá oooo. Ìsèsi á gbè wá o.
Read More »Àgbàrá òjò ní ìlú Benin látàrí òjò nlá tí ó rò lánàá.
Àgbàrá òjò ní ìlú Benin látàrí òjò nlá tí ó rò lánàá. Ní òpópónà Uselu ní ìlú Benin ti ìpínlè Edo ni àgbàrá ti gbalè gbalé léyìn òjò ñlá tí ó rò . òpòlopò okò ti omi gbé lo, òpó ...
Read More »Èèmò lukutu pébé ní ilé-èkó gíga ìfáfitì ti Ilé-ifè : Nígbà tí akékòó kan ya wèrè nígbà tí ó n kàwé lówó.
Gégé bí a ti mo wípé òkan gbógì ní ilé-èkó gíga Òbafemi Awolowo University (OAU) jé ní orílè èdè Nìjíríà yí. Sà déédéé ni a gbó wípé arábìnrin kan tí ó jé akékòó ilé-èkó yí ya wèrè látàrí ìwé kíkà ...
Read More »Odún dé, ore yèyé òsun.
Òsun Osogbo tún ti dé lónìí tí se ojó ketaàdínlógún osù kejo odún, 2018, tí gbogbo àgbàyé fi n se odún fún Òsun éléyinjú àánú, igbómolè obìnrin Òsàyòmolè Nílé ìyà olúgbón won kò gbodò mawo Ìran arèsè kò gbodò morò ...
Read More »Gbajúgbajà òsèré Olu Jacob mò wípé àgbàtó omo ni mí báyìí ni Joke Silver se so.
Gbajúgbajà òsèré, Joke Silver so wípé nse ni olóògbé E.A Silver àti Dr.Abimbola Silver gba òun tó ni sùgbón nse ni kìí se wípé òun kò mò télè . Joke Silver so wípé nígbà tí ó yá ni oko òun ...
Read More »Ooni ti Ilè- ifè , Oba Adeyeye Ogunwusi Enitan ti setán láti fé Tope Adesegun gégé bí olorì tuntun.
oni ti ilè-ifè , Oba Adeyeye Ogunwusi tí òun àti olorì télè èyí tí a mò sí olorì Wuraola tí pínyà ní osú ògún tí a mò sí odù kejo odún 2017, nse ni ó dàbí baba ti rí olólùfé ...
Read More »Arákùnrin tí ó jé omo Ebonyi, ìpínlè kan ní orílè èdè Nìjíríà yí ti kú sí ilè Italy pélù àwon mókànlá míràn.
Èyí bani ní inú jé púpò, arákùnrin tí ó jé omo orílè èdè Nìjíríà yí ti kú pèlú àwon mókànlà míràn ní inú ìjàmbá okò tí ó selè ní Foggia ní ilè Italy. Gégé bí ìròyìn se so, olóògbé yí, ...
Read More »Omobìnrin kékeré yí ni won dáné sun nígbà tí won fi èsùn kàn án wípé àjé ni, ní ìpínlè Akwa Ibom.
Àwòrán tí ó wà ní ìsàlé yí ni àwòrán omobìnrin kan tí orúko rè a máa jé Queen, won dáné sun omo yí látàrí èsún tí won fi kàn án wípé Àjé ni. Anja Louvre tí ó jé panépané ní ...
Read More »Àràbà Aworeni Adisa Makoranwale sun re.
òní tí ó jé ojó kokànlá osù kejo odún 2018 (11/8/2018) ni ètò ìgbé òkú baba wa tí ó sísè ní ojo ìségun tí ó jé ojó kokànlél’ógbòn osú keje odún tí a wà (31/7/2018) sí isà . Ìjo International ...
Read More »Timi Dakolo pín àwòrán ti ó rewà ti ìyàwó rè pèlú omo méta ní London.
Gbajúgbajà olórin ti orílè èdè Nìjíríà, Timi Dakolo ti pín àwòrán ìyàwó rè àti àwon omo rè méta ní ìlú London, ó ko síbè wípé “wón tun ti dé baba wón tún ti dé”. Timi Dakolo ti ó jé omo ...
Read More »