Arákùnrin kan ni ó fi ìtò ara rè wè látàrí àpòjù ìmukúmu. Arákùnrin kan ni a rí ní Ayobo, agbègbè kan ní ìpínlè Èkó tí ó n fi ìtò ara rè wè tí ó rò wípé omi ni látàrí ìmukúmu ...
Read More »Ayé Kareem ti yí padà di òtun láti ìgbà tí ó ti ya àwòrán Ààre Macron- Alákoso rè ló so béè.
Óríre míràn ti to omo kékeré, omo odún mókànlá tí a mò sí Kareem Waris Olamilekan tí olórun fún ní èbùn kí ó ma ta nkan, ó ti ya ààre ilè Faransé tí a mò sí Ààre Emmanuel Macron, nígbà ...
Read More »Ìròyìn Òrofó ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.
1 Ààrẹ Buhari yóò dé lónìí láti orílẹ̀ èdè China. 2 Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọ̀ṣínbàjò gba àlejò àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọn gbé igbá orókè nínú ìdíje ìmọ̀ ẹ̀rọ ìgbàlódé. 3 Àwọn oníròyìn ń fi ìròyìn burúkú bá ìjọba Buhari ...
Read More »Arábìnrin kan ni ó bí ìbeta léyìn odún métàdínlógún tí ó tí se ìgbéyàwó.
Arábìnrin kan ni ó gbe lo sí orí èro ayélujára tí a mo sí facebook láti lo pín ìròyìn ayò wípé òhun bí ìbeta láti bí odún métàdínlógún sèyìn. Ó ko síbè wípé… ” èyin abiyamo mi ò le mú ...
Read More »Àwon omo egbé APC ti Gúúsù Oyo ti jóòkó ìgbìmò – Abiola Ajimobi lo kí Alaafin Oyo.
Gómìnà ìpínlè Oyo , Abiola Ajimobi , tí ó ti fi okàn àwon omo egbé APC ti ìpínlè Oyo lókàn balè wípé omo egbé àwon ló ma wolé ní ibi ìdìbò tí ó n bò lónà ní odún 2019, àti ...
Read More »Owó àwon àgbófinró ti te olùsó tí ó fi ipá bá omobìnrin rè òdún méje sún.
Owó àwon àgbófinró ti te olùsó tí ó fi ipá bá omobìnrin rè òdún méje sún. Olùsó Daniel Udoh, tí ó dá ilé ìjosìn “Agbejórò ni jésù” sílè ni owó sìkún ìjoba ti tè ní Akapabuyo, ìpínlè Cross river látàrí ...
Read More »Gómìnà Aregbesola gun orí okò láti polongo egbé won tí a mò sí APC.
Gómìnà Aregbesola gun orí okò láti polongo egbé won tí a mò sí APC. Gómìnà ìpínlè Osun tí a mò sí Ogbeni Rauf Aregbesola ti gun orí ténté okò láti polongo egbé won, egbé oní ìgbálè tí a mò sí ...
Read More »Akékòó bìnrin méjì ja ìjàgbara látàrí òrékùnrin ní ilé-èkó gíga ifáfitì tí a mò sí Tai solarin University of Education, ní ìpínlè Ogun.
Fídíò àti àwòrán àwon òdóbìnrin méjì tí ó ñ jà látàrí òrékúnrin kan ni ó ti gbalè kan . Akékòó ni àwon arábìnrin méjì yí àti wípé akékòó ilé-èkó ifáfitì ti Tai Solarin University Of Education ni won, ìpínlè Ogun, ...
Read More »Davido ti darapò mó àwon àgùnbánirò láti sin orílè èdè rè.
Gbajúgbajà olórin ìgbàlódé ti a mò sí Davido ti darapò mó àwon àgùnbánirò láti sin orílè èdè rè. Davido tí ó jé omo ogbó-n-tarìgì àti èèyàn ñlá, tí ó sì jé omo tí ó ti ìdílé olórò wà súgbón tí ...
Read More »Akékòó ilé-èkó gíga tí a mò sí Polytechnic ti ìlú Ede ní ìpínlè Osun ni àwon ará ìlú ti lù pa .
Ní àná ni akékòó ilé-èkó ti poly Ede fi okò pa ènìyàn bíi márùn-ún tí àwon omo tí ó sèsè fé wo ilé-èkó náà pélù okò rè. Bí ó tilè jé wípé, àwon ojú tí ó wà níbè náà so ...
Read More »