Ise awon asaraloge ni ki won tunrase. Sugbon nigba mi-in, won tun le baraje. Sebi bise ba se gba ni won se n se e. Ise opolo ni ise tiata, awon onitiata ni won se ise opolo. Foto: eni ti ...
Read More »
admin Comments Off on E wa wo ise opolo to fakiki
Ise awon asaraloge ni ki won tunrase. Sugbon nigba mi-in, won tun le baraje. Sebi bise ba se gba ni won se n se e. Ise opolo ni ise tiata, awon onitiata ni won se ise opolo. Foto: eni ti ...
Read More »admin Comments Off on Yanju Adegboyega: Ohun ti won wi ti ko koreeti”
“Nje e mo pe “oye to kan ara Iwo, o n bo wa kan ara Ede, tawon kan maa n wi yen ko koreeti? Ilu kan n be ni ka to de Ede ti won n pe “Awo”, ilu yii ...
Read More »admin Comments Off on Ile ejo ti ran Jimoh lewon leyin to fi ehin ja ori oyan asewo niluu Ibadan
Ile ejo ti ran Jimoh lewon leyin to fi ehin ja ori oyan asewo niluu Ibadan Orisun Oniroyin: Twitter Ile ejo Majisireeti ti n jokoo niluu Ibadan ti ran Ogbeni Sunday Jimoh lewon bayii leyin igba to fi ehin ja ...
Read More »admin Comments Off on Won je David Mark, Amaechi ati Fasola lenu bi obi abata
Orisun Oniroyin Twitter Won je David Mark, Amaechi ati Fasola lenu bi obi abata *Didake David Mark n ko awon eniyan lominu *Asa tuntun ti won da: “Mi o gba riba ri laye mi” – Amaechi “Gege bi gomina, mi ...
Read More »admin Comments Off on Ewi Awon Omode: E Ma Ya Baseje
Ewi: E ma ya baseje Eyin ewe iwoyii, e wa teti si agogo ogbon E ma ya baseje Baseje ti n bale je ni won pe larungun Arungun ni eni ti n ba ohun ti won fowo se je ...
Read More »admin Comments Off on Itan fun awon omode: Kinihun ololaaju ati eku inu igbo
Orisun Kinihun ololaaju ati e ku inu igbo Itan ti a fe gbe yewo lonii ni itan Kinihun ololaaju ati eku inu igbo. Gbogbo wa la mo wi pe kinihun loba eranko. Oun naa si ni eranko to lagbara ju ...
Read More »admin Comments Off on Mooko-mooka: Akoto ede Yoruba
Mooko-mooka: Akoto ede Yoruba Ni abala mooko-mooka ose yii, akoto ede Yoruba ni a maa gbe yewo. Akoto je ona ti n gba ko ede Yoruba sile laye ode-oni. Eleyii to yato si ti aye atijo. Aye Atijo Aye ...
Read More »admin Comments Off on Awon omo onimoto da gobe sile ni ipinle Ondo
Orisun Awon omo egbe onimoto NURTW eka ti ijoba ibile Owo to kale si ipinle Ondo buta sira won loju lojo Isegun to koja yii. Awon iko meji kan ti won je ti egbe NURTW la gbo wi pe won ...
Read More »admin Comments Off on Nje ohun to buru wa ninu ara bibo?
Nje ohun to buru wa ninu ara bibo? Idahun awon eniyan wa ninu linki isale yii: https://www.facebook.com/photo.php?fbid=904657846286766&set=gm.1070531176331524&type=3
Read More »BalogunAdesina Comments Off on Onka ede Yoruba 100 – 20,000
Orisun Onka ede Yoruba 100-Ọgọrun 110- Adọfa, àádọ́fà 120- Ọgọfa 130- Aadoje 140- Ogoje 150- Adọjọ, àádọ́jọ 160-Ọgọjọ 170-Adọsan, àádọ́sán 180- Ọgọsan 190-Mẹwadinigba 200-Igba E tesiwaju ni isale lẹhin iwe Bireki yii (Continue after the page break bellow)
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more