Ọ̀rọ̀ ti di olójú ò níí yajú ẹ̀ sílẹ̀ kí tàlùbọ̀ ó yíwọ̀ọ́ àti pé ọmọ onílùú kò níí fẹ́ ó tú lọ̀rọ̀ dà báyìí ó, bí.
Read More »
ayangalu Comments Off on Àmọ̀tẹ́kùn: Ẹ̀ṣọ́ ilẹ̀ Oòduà (Yorùbá) ‘Àmọ̀tẹ́kùn’ ṣetán láti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ káàkiri ilẹ̀ káàárọ̀ o ò jíire
Ọ̀rọ̀ ti di olójú ò níí yajú ẹ̀ sílẹ̀ kí tàlùbọ̀ ó yíwọ̀ọ́ àti pé ọmọ onílùú kò níí fẹ́ ó tú lọ̀rọ̀ dà báyìí ó, bí.
Read More »ayangalu Comments Off on Ìdí tí a fi yọ Donald Trump nípò Ààrẹ
Alágbára ayé,alágbára ayé,a sè a ṣẹ̀ má lù kan, Ọlọ́run o tíì da sí dúníyàn .Bí nǹkan se n lọ yìí, Donald Trump ni Ààrẹ orílẹ̀èdè Amẹ́ríkà kẹta nínú ìtàn tí ọ̀bẹ yóó bá ń dìí láti ọ̀dọ̀ àwọn Ilé ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ìdájọ́ Ilé ẹjọ́ kò sọ pàtó ẹni tó jáwé olúborí láàrín Makinde àtiAdelabu
Ìdájọ́ Ilé ẹjọ́ kò sọ pàtó ẹni tó jáwé olúborí láàrín Makinde àtiAdelabu Fẹ́mi Akínṣọlá Kángun kàngùn Kángun, bọ́ pẹ́,bọ́ yá, ó gbọ́dọ̀ kángun síbìkan, bẹ́ẹ̀ ló súmọ́ kí ọ̀rọ̀ rí ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, látàrí àgbéjáde ilé ẹjọ́.Tí Ilé ẹjọ́ ...
Read More »ayangalu Comments Off on O lè wọ sòkòtò tó tóbi, ṣùgbọ́n kò sí ààyè fún yẹ̀rì,láti sìnrúùlú …Àjọ àgùnbánirọ̀. (NYSC)
O lè wọ sòkòtò tó tóbi, ṣùgbọ́n kò sí ààyè fún yẹ̀rì,láti sìnrúùlú …Àjọ àgùnbánirọ̀. (NYSC) Fẹ́mi Akínṣọlá Ọ̀gá àgbà fún àjọ àgùnbánirọ̀ lórilẹ̀-èdè Nàìjíríà, Brig. Shuaibu Ibrahim ti sàlàyé fún akọ̀ròyìn pé ààyè wà fún àgùnbánirọ̀ tó bá fẹ́ ...
Read More »ayangalu Comments Off on N kò leè fi ìdúnú mi pamọ́ lọ́jọ́ ìkómọ àwọn ìbẹta….Yinka Ayefele
N kò leè fi ìdúnú mi pamọ́ lọ́jọ́ ìkómọ àwọn ìbẹta….Yinka Ayefele Fẹ́mi Akínṣọlá Ẹ̀dá ò láròpin láyé, ṣé bí ó se wu Olúwa Ọba níí sọlá, fẹ́ni Ó wù ú,bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ ni ọ̀rọ̀ níbi tí t’ọba, tìjòyè, ọ̀tọ̀kùlú ìlú ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ọmọọba mẹwàá ló du òyè pẹ̀lú mi – Aláàfin Ò̩yó̩
Ọmọọba mẹwàá ló du òyè pẹ̀lú Adeyẹmi, tó sì já mọ lọ́wọ́. Fẹ́mi Akínṣọlá Ọlayiwọla Adeyẹmi Kẹta, ti pé ẹni ọdún mọ́kànlélọ́gọ́rín lókè eèpẹ̀ bẹ́ẹ́ ló ti lo ọdún méjìdínláàdọ́ta lórí ìtẹ́ àwọn baba ńlá rẹ̀. Òjò ti ń pa ...
Read More »Kini Oruko ti won pe kokoro ti o wa ninu aworan oke yii ?
Read More »ayangalu Comments Off on Oòduà Words Of the Week
Báyií – This is how, Báwo? -How? Bákan – Somehow, Bádé – Arrived withBálo =Go withBárò =Commeserate
Read More »admin Comments Off on Adanwo ni oro ile aye: Iku Abubakar Audu gba arojinle
Titi di akoko yii, enikeni ko le so pato ohun to sekupa oludije ipo gomina labe egbe oselu APC ni ipinle Kogi, Abubakar Audu. Se ise aye ni abi amuwa Olorun oba? Ohun ti ko ye enikan, kedere ni niwaju ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more