Aare ilu South Africa, Jocob Zuma, ti fi owo si abadofin lati maa sami si egbe kan oju ara awon ti won ba ni kokoro HIV lara. Won ni nipa sise eleyii, yoo mu adinku ba awon eniyan ti won ko kokoro naa. Won si ro awon eniyan bi milionu mewaa eleyii ti ayewo ti fi han wi pe won ni kokoro naa lara lati wa gba amin naa, eleyii ti won se bi tattoo. Bakan naa ni won se ileri ebun owo fun awon to ba yoju
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more


Lobatan.