Musiliu Obanikoro ti fi tòwòtòwò darapò mó egbé APC.
Olóyè Musiliu Obanikoro ti fi tòwòtòwò fi egbé alásìá, PDP (People Democratic Party)sílè lo dí egbé onígbálè APC (All Progressive Congress). Ìròyìn jé kí á mò wípé ìgbésè Obanikoro lo sí egbé tuntun ti bèrè láti bi osù mélòó séyìn ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more











