Home / Art / Àṣà Oòduà (page 44)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Àgbàrá òjò ti gbalé gbalè ní ìlú ilé-ifè ní àná tí Òpò akékòó kò sì rí àyè lo sí ilé-èkó.

   Gégé bí a ti mò wípé ilé-ifè jé ìlú tí ilé-èkó gíga wà, tí ó sì kún fún àwon akékòó bíi àwon akékòó ilé-èkó gíga ifáfitì ti Obafemi Awolowo university (OAU) àti ilé-èkó gíga ifáfitì ti Oduduwa university ilé-ifè ...

Read More »

Simi kúnlè ní orí ìtàgé láti kí ògbóntarìgì olórin tí a mò sí Lágbájá, nígbà Ó ń dá àwon èèyàn lárayá lówó.

Simi tí síde ayeye tí Jannie, Jazz àti Whisky pè ní ìlú Abuja ní alé ojó náà, Simisola jungle ní orí ìtàgé láti kí eni ńlá, èníyàn pàtàkí àti gbajúgbajà olórin láti dá àwon èníyàn lárayá papò. Ògbóntarìgì olórin tí ...

Read More »

Omiyalé, àgbàrá ya sóòbù ní ìlú ilé-ifè.

Ní òwúró ojó àíkú tí se èní,ojó kokàndínlógbòn osù keje odún 2018 ni òjò yí bèrè tí ó sì kò tí kò dáké di bíi agogo márùn-ún ìròlé. Èyí fa kí àgbàrá ya wo ilé tí ó pò ní òpópónà ...

Read More »
obatala

Obàtálá

Obàtálá (Ìwà) Amúyan abìtanná yanranyanran Adia’fun orunmila babá o tanná fórìsà riwa Ebo lawo ni kose Ógbébo órúbo Ógbèrù ótèrù Njé ifá tan sílé, èdú tan sónà Tan ni o mòpé ina ire lope ntan Bàbá arúgbó that: Sleeps in ...

Read More »

ÀWỌN JAGUNJAGUN WA

Ó yá, Ẹ jẹ́ á sàm̀bátá àwọn jagunjagun wa. Ẹ jẹ́ ká f’orin ọgbọ́n yẹ̀ wọ́n wò, Ká mọ rírì isẹ́ wọn t’ó yakin. Pàtàkì l’àwọn ológun lórílẹ̀-èdè yìí; Ișẹ́ takuntakun ni wọ́n kúkú ń ṣe. Mo kírà f’áwọn sójà ...

Read More »

Omokùnrin odún méèédógún tí orúko rè ńjé Okorogheye David ni ó peregedé jùlo nínú ìdánwò àsekágbá ti ilé-èkó

Omokùnrin odún méèédógún yí gba máàkì tí ó pò jùlo nínú ìdánwò àti wo ilé-èkó gíga ifáfitì tí ó sì gba púpò jùlo nínú WAEC. Omokùnrin yí gba àmì A nínú gbogbo ìdánwò tí Ó se fún WAEC tí Ó ...

Read More »

ÈDÈ YORÙBÁ

ÈDÈ YORÙBÁ Èdè Yorùbá ṣe pàtàkì; Ó ṣe kókó. Ẹ̀yin ọmọ Oòduà, Ẹ jẹ́ ká máa rọ́jú s’èdèe wa. Èdè òǹluko kọ́ l’èdèe Yorùbá. Èdè tó gba’yì tó gb’ẹ̀yẹ ni. Àìkọ́mọ l’áhọ́n-ìbílẹ̀, Ní sábàbí ìwà ọ̀yájú. Ọmọ yín jí ní ...

Read More »

Won ti ojà ní Abeokuta láti fi se àpónlé fún Oba won tí ó di olóògbé.

Ojà tí ó wà ní ìlú Abeokuta ní won tì pa pátápátá ní àná, won se èyí láti fi se àpónlé Oba won tí ó wàjà eni tí a mò sí Oba Halidu Laloko (MFR) tí ó jé Agura ti ...

Read More »

Tuface àti àwon omo rè okùnrin méjì Nino àti Ziona Idibia ní New York.

Tuface àti àwon omo rè okùnrin méjì Nino àti Ziona Idibia ní New York. Gbajúgbajà tí ó tún jé ògbóntarìgì olórin ìgbàlódé ti a mò sí Tuface Idibia tí ó wà ní orílè èdè United State báyìí fún ìrìn àjò ...

Read More »

Àwon ajínigbé àti omo egbé òkùnkùn mérin ní ìpínlè River

Àwon ajínigbé mérin tí won tún jé omo egbé òkùnkùn tí ńkó da ìjoba ìbílè Eleme àti agbègbè rè láàmú ni àwon olùbódàbòbò pa . Orúko àwon tí won pa a máa jé Joe Mba tí ìnagije rè ńjé Sk ...

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb