Olórí àwon olùfokànsìn àti omo léyì jésù ti Ìjo àwon RCCG, gbogbo àgbáyé, Pásítò E.A Adeboye fún àwon akékòó tí won sèsè gboyè gégé bíi adájó mérin nínú ìjo rè ní àgbàlá HALL OF MERCY, Bwari ní ìpínlè Abuja, ní ...
Read More »Àwon àwòrán tí ó rewà tí Lota Chukwu fi se ayeye ojó ìbí rè nígbá tí ó pé omo odún mókàndínlógbòn (29).
Àwon àwòrán tí ó rewà tí Lota Chukwu fi se ayeye ojó ìbí rè nígbá tí ó pé omo odún mókàndínlógbòn (29). Gbajúgbajà arewà òsèré orílè èdè Nìjíríà tí ó n jé Lota Chukwu se ayeye odún mókàndínlógbon ojó ìbí ...
Read More »Arábìnrin omo odún méèdógbòn, tí ó tún jé a fi ewà s’oge, Chidimma Leilani Aaron ti gba àmì èye gégé bíi omidan àkókó ní orílè èdè Nìjíríà tí odún 2018.
,Chidimma Leilani Aaron, omo odún méèdógbòn láti ìpínlè Enugu ti tayo àwon métàdínlógún (17) tí won jo díje fún omidan àkókó ní orílè èdè Nìjíríà ti odún yí. O di eni kejìlélógójì tí yóò gba àmì èye yí ó sì ...
Read More »Tobi Bakre ya àwòrán pèlú Rita Dominic, Lolu, Bovi àti Ebuka.
Ará ilé BBNaija télè tí ó sì jé àyànfé òpò ènìyàn tí a mò sí Tobi Bakre lo sì orí èro ayélujára rè tí ó n jé Insítágírámù láti pín àwòrán òhun àti àwon ènîyàn pàtàkì bíi Rita Dominic, Lolu, ...
Read More »Truth!
Òsá Òtúrá says, “What is Truth?” I say, “What is Truth?” Ọ̀rúnmìlá says, “Truth is the Lord of Heaven guiding the Earth.” Ọ̀rúnmìlá says, “Truth is the Unseen One guiding the Earth. The wisdom of Olódùmarè he is using.” Òsá ...
Read More »Following the Reaper Gleaners of Eji Koko Iwori
Eni a ba wa’de Laa ba rele Eni aja bawa laja nba lo Dia fun Eleji Iwori Ti yoo teju no akapo re girigiri Ebo ni won ni o wase O gbebo, o rubo Ifa teju mo mi koo wo ...
Read More »Goodluck Ebele Jonathan se ayeye odún mókànlélógóta (61) ojó ìbí rè ní èní.
Goodluck Ebele Azikiwe Jonathan GCFR GCON tí won bí ní ogún’jó osù Belu ní odún 1957, tí ó jé olósèlú ní orílè èdè Nìjíríà tí ó sì sin ìlú gégé bíi Ààre orílè èdè Nìjíríà láti odún 2010-2015. Kí ó ...
Read More »Obatala visits Wole Soyinka at age 83
By Bode Sowande I gave a public lecture at the Schomburg Centre, Harlem, New York in the late 90s and the subject of homosexuality was addressed by me, and one theatre director accused me of intolerance. The sum of my ...
Read More »Kí ni ojú ò rírí, kárí ká f’ojú fò lópò. Njé Eléhà ninèyí tàbí Egúngún?.
Òrò náà só síni lénu ó tún buyò si, àbí bí èèyàn yóò bá jé òsákálá kí ó jé Òsákálá bí yóò sì jé Òsokolo kí ó ké Òsokolo, èwo ni òsákálásokolo. Èyí èèyàn sé Eléhà ni a ó pe ...
Read More »“Where was Ifa when our Ancestors walked alone during slavery” ?
Many do not understand what Ifa represent today or what it is all about and this has generated heated argument all around the world among scholars. Up to the point when the Araba of Oworonsoki posted, “with Ifa you will ...
Read More »