Home / News From Nigeria / Breaking News (page 159)

Breaking News

Àwon ìbeta tí ó rewà yí tí ewà won sì wuni yí se ayeye ojó ìbí won pèlú àwòrán tó yááyì.

John, Peter àti Jamie Obidiegwu, ìbeta se ayeye ojó ìbí won ní àrà òtò. Ayeye ojó ìbí míràn ni ó jé fún àwon ìbeta tí ó jé okùnrin yí, ohun ayò ni ayeye yí sì jé fún won tí won ...

Read More »

Ìgbeyàwó alárédè ti DJ consequences àti Olayemisi Williams.

Arákùnrin tí ó ń se isé DJ tí a mò sí DJ consequences àti aya rè Olayemisi Williams ti se ayeye ìgbeyàwó won. A kí tokotayà kú oríre .

Read More »

Tboss se ayeye ojó ìbí fún ìyá rè àgbà ti ilè Roman

Tboss se ayeye ojó ìbí fún ìyá rè àgbà ti ilè Roman. Ará ilé télè ti BBnaija tí a mò sí Tokunbo Idowu tí ìnagije rè ń jé Tboss, ti se ayeye ojó ìbí fún ìyá rè àgbà ti ilè ...

Read More »

Yorùbá mothers ! (Interesting Read)

Yorùbá mothers are the best when it comes to child upbringing. Yorùbá mothers produce the best range of slaps: IGBATI, IFOTI, IGBAJU, IGBARUN IFORUN, IFAKUN, ILADI, ABARA. These slaps will make you think you were adopted. IGBATI will make you ...

Read More »

What is the Month of July In Yoruba ?

 

Read More »

Àgbàrá òjò gbé èèyàn méjì lo ní UNN, Nsukka, tí ó sì pa wón.

Èèyàn méjì òtòtò ni ó di olóògbé látàrí àgbàrá òjò tí Ó gbé won lo, tí Óní sì pa wón sí gbàgede enu àbáwolé ilé-èkó gíga ifáfitì ti orílè èdè Nìjíríà, Nsukka (UNN). Gégé bí ìròyìn se so àwon olóògbé ...

Read More »

Wizkid àti ìyá rè ya àwòrán papò.

Gbajúgbajà olórin afé tí a mò sí starboy, tí Óní tún jé Wizkid ya àwòrán pèlú ìyá rè. Èyí wùwá ooo.

Read More »

Odun odun kan ko dun dun

Ko dun bi odun yi ri Odun ti o dun ni odun ominira1960 Odun n dun ni dundun n dun Orile-ede ti n San fun wara ati oyin Orile-ede abinibi Nigeria Adugbo ti n toro omo ale ni ke ti ...

Read More »
NYSC

ỌJỌ́ NÁÀ RÈÉ BÍ ÀNÁ

  Ọjọ́ náà rèé bí àná. Bí eré bí àwàdà; Kánmọ́kánmọ́ l’ọjọ́ ń șí lọ bí ẹyẹ. Ọjọ́ náà rèé bí àná; Tá a bẹ̀rẹ̀ ìgbésẹ̀ ìrìn-àjò ọ̀hún. Òjòó rọ̀ wọ̀wọ̀. Afẹ́fẹ́ fẹ́ ilẹ́lẹ́-ilẹ́lẹ́. Ẹ̀fúùfùlẹ̀lẹ̀ẹ́ m’igi oko dìgbàdìgbà. Ojúu sánmọ̀ọ́ ...

Read More »
fela

Fela Kuti’s Africa Shrine: A place of honor to be visited by the President Macron of France – QOTD

“Fela Kuti’s Africa Shrine that the successive Nigerian military and civilian governments considered to be the dens of drug dealers, drug addicts, prostitutes and nuisance was considered a place of honor to be visited by the President Macron of France.” ...

Read More »

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb