Davido àti Kiss Daniel nínú o okò ojú òfurufú. Gbajúgbajà olórin àti ìlú mòóká olórin tí gbogbo ayé mò sí Wizkid àti Kiss Daniel ya àwòrán papò nínú okò ojú òfurufú aládani. Nse ni ó dàbí eni wípé won fé ...
Read More »Toke Makinwa nínú aso ìwè nígbà tí ó lo sí èbá òkun ní ìlú Èkó.
Gbajúgbajà ò n lò èro ayélujára tí a mò sí Toke Makinwa tí gbé ògo tí olórun fún hàn, nígbà tí ó gbé àwòrán ìgbà tí ó wo aso ìwè sí orí èro ayélujára tí ó n jé Ínsítágírámù . ...
Read More »Gbajúgbajà olórin tí a mò sí Yemi Alade rèdí fún, ìlúmòókà olórin tí a mò sí Flavour.
Gbajúgbajà olórin tí a mò sí Yemi Alade rèdí fún, ìlúmòókà olórin tí a mò sí Flavour. Gégé bí òrò ata díndín tí ó gbòde kan, òrò nípa Tiwa Savage àti Wizkid tí àwon èèyàn n gbà, tí won sì ...
Read More »Ogbè Ògúndá (Ogbèyọ́nú)
Ifá pé òun yóò ṣe oore òjijì fún ọmọ Ogbèyọ́nú tàbí ẹni yòówù tí a dáfá yìí fún. Ifá pé ìgbàgbọ́ rẹ̀ kò tó nǹkan nínú òun; pé kó lọ ní ìgbàgbọ́ tó jinlẹ̀ síwájú síi nínú òun Ọ̀rúnmìlà. Ifá ...
Read More »Oònirìsà sòrò nípa bí àwon èèyàn se n so kiri wípé èjè ni olorì tuntun tè mólè.
Oònirìsà sòrò nípa bí àwon èèyàn se n so kiri wípé èjè ni olorì tuntun tè mólè. Oònirìsà ti jé kí á mò wípé yèyélúwà kò te èjè mólè rárá àti wípé Osùn ni Oluwaseyi Moronke, Yèyélúwà tuntun tè mólè ...
Read More »Kò kò, ó gbà láti se ètùtù, Moronke Naomi Oluwaseyi gbà láti se òun tótó gégé bí olorì àkókó láàrin àwon olorì pátápátá.
Bí won se ni kó se é ló se é. Bí ó tilè jé wípé àtúnbí nínú Jésú ni, kò kò láti se àwon ohun tí ó tó gégé bí olorì láàfin Oòni ti ilé-ifè. Àwòrán ibi tí ìyàwó ti ...
Read More »Bí ò bá dùn yóò pé, bí ó bá pé yó dùn; Òònirìsà fé ìyàwó tuntun.
Bí ò bá dùn yóò pé, bí ó bá pé yó dùn; Òònirìsà fé ìyàwó tuntun. Sùúrù tí ó lójó ni Omo Ogunwusi fi se, Aláse èkejì Òrìsà so Naomi Oluwaseyi Silekunola di Olorì láàfin rè. Èyin omo odùduwà e ...
Read More »Alex Asogwa di onílè púpò ní Omo odún méjìlélógún (22).
Ará ilé Big Brother Naija télè tí a mò sí Alex Asogwa tí ó sèsè towó bo ìwé pèlú ilé-isé tí ó n ta ilè tí ó tún ń ta Ilé, ilé-isé real estate and investment company.Alex Asogwa ti gbe ...
Read More »KÍ LÓ BÀJẸ́ LÉDÈ WA
Ẹ jẹ́ kí a tibi pẹlẹbẹ mú ọ̀lẹ̀lẹ̀ jẹ. N jẹ́ fífi gẹ̀ẹ́sì kọ́ni lédè Yorùbá le múni yege dáada nínú ẹ̀kọ́ èdè Yorùbá bí? Gẹ́gẹ́ bíi òwe gẹ̀ẹ́sì kan tí ó wí pé, “the best way to understand a ...
Read More »Odún pé, odún jo, àmòdún wa èsín pé.
Ikú bàbá yèyé, Aláse èkejì Òrìsà, baba wa Aláàfin ti ilè Òyò, Oba Lamidi Adeyemi 111 se ayeye ojó ìbí rè ní òní tí won pé ogórin odún (80). Àrà méèrírí ni kábíèsí, Ikú bàbá yèyé nítorí baba ni wón ...
Read More »