Ogbontarigi agbaboolu omo Naijiria, Ahmed Musa, ti n le waju bayii ninu awon agbaboolu to rawon julo niluu Russia. Iroyin yii jade ni kete ti egbe agbaboolu re, CSKA Moscow jawe olubori nigba ti won pade pelu Dynamo pelu ayo ...
Read More »Ara Orisiirisii Nibi Igbeyawo Aye Ode Oni
Iru sitayi wo leyii?
Read More »Ohun to mu Odun Ominira eyi yato si ti igba ti Goodluck Jonathan wa lori oye
Ara opo awon omo Naijiria tun ya gaga si orile ede won lojo Alamisi to koja, nigba ti a se ayeye ominira odun karunlelaadota. Kaakiri awon ipinle, opo eniyan lo ki akegbe won ku oriire, ti won si n soro ...
Read More »Ajimobi ati Amosun Da Ara Ilu: Won Ni Ko Si Eko Ofe Mo
Lati inu iwe Iroyin Owuro to jade lose to koja ni iroyin naa ti jade wi pe Ajimobi ati Amosun ti pada ninu ileri eto eko ofe ti won se ileri re fun awon ara ilu. Won ni ki olomu ...
Read More »Se Eyin Ri Iru Aso Igbeyawo Bayii Ri?
E leyii tun leku!
Read More »E Wa Wo Ohun Ti Omokekere Yii Da Lara: Eleyii Koja Afenu So
Lara awon iroyin wa to ti jade tele, awon iroyin lori ate Olayemi Oniroyin, mo se lalaye wi pe Edua Oke ko da ile Adulawo gege bi ibugbe awon otosi ati alaini; awon olori wa lo so ilu wa di ...
Read More »Omo Naijeria Setan Lati Dije Fun Ipo Aare Orileede Spain
Ko to di wi pe ma kan lu agbami oselu ti n gbona felifeli bayii ni ilu Spain, nibi ti Arabirin Helen Mukoro to je omo ipinle Delta lati orileede Naijeria ti setan lati dije fun ipo aare orileede Spain, ...
Read More »E Wo Ohun Ti Awon Omo Ile Igbimo Asofin Se Lodun 1962
Awon omo ile igbimo asofin Nigeria ti n foganna lojo to ti pe, ohun ti won se ni yii lodun 1962 nigba rogbodiyan Western Region. Orisun
Read More »Odaju Abiyamo Fi Ina Jo Omobirin Eni Odun Merindinlogun Loju Ara: O Ni Omo Naa N Se Agbere
Omobirin odaran kan ni owo awon olopaa ti te ni agbegbe Ketu niluu Eko pelu bo se fi ero ayoonu iloso jo omo egbon re ti n gbe pelu re, Bimpe Badmus, omo odun merindinlogun, nidi pelu esun wi pe ...
Read More »Bi odun yi se n pari lo a ko ni ri ogun ewon !
lase Edumare
Read More »